×
Image

Ojise Aanu - (Èdè Yorùbá)

1- Oro lori koko ohun ti Olohun fi ran ojise Re Muhammad, iranse ni o je si gbogbo aye patapata. 2- Pelu bi o ti je wipe awon osebo fi inira kan ojise Olohun ni ilu Makka sibe sibe o tun fi aanu bawon lo ti ko si fi ibi....

Image

Mimu Ọlọhun ni Ọkan nibi Awọn Ise Rẹ ( Taohiidur-Rubuubiyyah ) - (Èdè Yorùbá)

Itumọ Mimu Ọlọhun ni Ọkan soso nibi Awọn Ise Rẹ (Taohiidur-Rubuubiyyah) ati awọn ẹri lori rẹ, pẹlu awọn koko alaye ọrọ ti rọ mọ ọn

Image

Mimu Ọlọhun ni Ọkan Soso nibi Isẹ Awa Ẹda ( Taohiidul-Uluuhiyyah ) - (Èdè Yorùbá)

Itumọ Mimu Ọlọhun ni Ọkan Soso nibi Isẹ Awa Ẹda ( Taohiidul-Uluuhiyyah ) pẹlu alaye wipe Taohiid yii ni o maa nda ija silẹ laarin awọn ojisẹ ati awọn ijọ wọn

Image

Sise Olohun ni Okansoso ati Awon Ipin Re - (Èdè Yorùbá)

Ibanisoro yi da lori sise Olohun ni okan soso ati awon ipin re meteeta. Olubanisoro si se alaye ni ekunrere eyi ti o se pataki julo ninu awon ipin wonyi ti opolopo Musulumi ni asiko yi si nse asise ti o fi oju han nibe.

Image

Sise Ọlọhun ni Ọkan Soso nibi Awọn Orukọ Rẹ ati Iroyin Rẹ - (Èdè Yorùbá)

1- Awọn akori ọrọ ti o jẹyọ ni abala yii ni wọnyii: (i).Itumọ sise Ọlọhun ni Ọkan soso nibi Awọn Orukọ Rẹ ati Iroyin Rẹ. (ii). Alaye lori awọn ti wọn lodi si Sunna nibi ilana yii. 2- Alaye nipa ilana awọn ti won tẹle Sunna nibi orukọ Ọlọhun ati....

Image

Kini An Peni Imo Olohun Lokan - (Èdè Yorùbá)

Kini An Peni Imo Olohun Lokan

Image

Orukọ Ọlọhun ( Ar-Rahmaan ) - (Èdè Yorùbá)

Awọn ohunatiaworanniede Yoruba pẹluakọle: [Awọn OrukọỌlọhunti O Rẹwajulọni sisẹ n tẹle], niapayiini a tiriOrukọỌlọhun [ Ar-Rahmaan ], pẹlu awọn itumọti O n tọkasi, ọnaakọsilẹ rẹsidaraniriri.

Image

Orukọ Ọlọhun ( Ar-Rọhiim ) - (Èdè Yorùbá)

Awọn ohunatiaworanniede Yoruba pẹluakọle: [Awọn OrukọỌlọhunti O Rẹwajulọni sisẹ n tẹle], niapayiini a tiriOrukọỌlọhun [ Ar-Rọhiim ], pẹlu awọn itumọti O n tọkasi, ọnaakọsilẹ rẹsidaraniriri.

Image

Orukọ Ọlọhun ( Al-A’fuwwu ) - (Èdè Yorùbá)

Awọn ohunatiaworanniede Yoruba pẹluakọle: [Awọn OrukọỌlọhunti O Rẹwajulọni sisẹ n tẹle], niapayiini a tiriOrukọỌlọhun [ Al-A’fuwwu ], pẹlu awọn itumọti O n tọkasi, ọnaakọsilẹ rẹsidaraniriri.

Image

Orukọ Ọlọhun ( Al-Gafuur ) - (Èdè Yorùbá)

Awọn ohunatiaworanniede Yoruba pẹluakọle: [Awọn OrukọỌlọhunti O Rẹwajulọni sisẹ n tẹle], niapayiini a tiriOrukọỌlọhun [ Al-Gafuur ], pẹlu awọn itumọti O n tọkasi, ọnaakọsilẹ rẹsidaraniriri.

Image

Orukọ Ọlọhun ( Al-Gaffaar ) - (Èdè Yorùbá)

Awọn ohunatiaworanniede Yoruba pẹluakọle: [Awọn OrukọỌlọhunti O Rẹwajulọni sisẹ n tẹle], niapayiini a tiriOrukọỌlọhun [ Al-Gaffaar ], pẹlu awọn itumọti O n tọkasi, ọnaakọsilẹ rẹsidaraniriri.

Image

Orukọ Ọlọhun ( Ar-Rọuuf ) - (Èdè Yorùbá)

Awọn ohunatiaworanniede Yoruba pẹluakọle: [Awọn OrukọỌlọhunti O Rẹwajulọni sisẹ n tẹle], niapayiini a tiriOrukọỌlọhun [ Ar-Rọuuf ], pẹlu awọn itumọti O n tọkasi, ọnaakọsilẹ rẹsidaraniriri.