Awon Ijeri Mejeeji
Awon Ijeri Mejeeji - (Èdè Yorùbá)
Lilo Si Ile Oluwa - (Èdè Yorùbá)
Lilo Si Ile Oluwa
Yiyo Zakaat - (Èdè Yorùbá)
Yiyo Zakaat
Gbigba Awe Ramadan - (Èdè Yorùbá)
Gbigba Awe Ramadan
Pataki titele Sunna Anobi Muhammad - (Èdè Yorùbá)
Oludanileko ninu eto yii soro nipa bi o ti se Pataki fun Musulumi ki o maa tele Sunna Anobi wa Muhammad
Gbigba Kadara gbo - (Èdè Yorùbá)
Akole yi so nipa bi o ti se je ojuse Musulumi ki o so enu aala Olohun nigba ti o ba n wa arisiki, ki o ma gba ona haraam ti Olohun ko fe lati fi wa oro. Ki o ma fi ibinu Olohun wa iyonu awon eniyan.
Ola ti o wa fun Eni ti o ba mo Olohun lokan - (Èdè Yorùbá)
Ibanisoro yi je ki a mo Pataki ki Musulumi mo Olohun re ni okan soso ki o si doju ijosin ko Olohun naa. Mimo Olohun ni okan (Taoheed) ni ipile esin, ohun si ni ohun ti o ye ki Musulumi moju to julo.
Awon Ohun ti o je Ojuse Eni ti o sese gba Esin Islam - (Èdè Yorùbá)
Oniwaasi so Pataki esin Islam o si je ki awon eniyan mo wipe gbigba esin Islam kiise mimoose enikan bikose aanu Olohun lori eni naa. Bakannaa o tun so iyato ti o wa laarin Islam ati awon esin yoku, ti o si so awon majemu ti o maa nje ki....
Igbagbo Ododo - (Èdè Yorùbá)
Ibanisoro yi da lori igbagbo ninu Olohun ati alaye itumo re. Olubanisoro yi se alaye pupo lori itumo ohun ti o nje igbagbo, o si fi awon apeere laakaye ba awon eniyan soro pupo nibe nitoripe eleyi ni o ba awon ogooro eniyan ti won wa ni ijoko naa mu.....
Ijosin Ninu Islam - (Èdè Yorùbá)
Ibanisoro yi da lori ijosin ati itumo re, oniwaasi so Pataki ki Musulumi se akiyesi awon majemu ijosin mejeeji: awon naa ni sise afomo ise fun Olohun ati sise ise ijosin naa ni ibamu pelu bi ojise Olohun ti se e. Lehinnaa ni o menu baa won oniran iran ijosin....
Sise Olohun ni Okansoso ati Awon Ipin Re - (Èdè Yorùbá)
Ibanisoro yi da lori sise Olohun ni okan soso ati awon ipin re meteeta. Olubanisoro si se alaye ni ekunrere eyi ti o se pataki julo ninu awon ipin wonyi ti opolopo Musulumi ni asiko yi si nse asise ti o fi oju han nibe.
Ojise Olohun Muhammad Ike ni o je fun Gbogbo Aye - (Èdè Yorùbá)
Olubanisoro se alaye bi ojise Olohun anabi Muhammad se je ike fun gbogbo aye, Olohun lo ojise naa lati se agbega fun awon iwa rere O si loo lati pa awon iwa buburu re. Olohun si da ojise re ni eniti o pe ni eda ati ni iwa.

API
