Ilana Muhammad – ki ikẹ ati ọla Ọlọhun maa ba a – nibi awọn ijọsin rẹ ati awọn ibaṣepọ rẹ ati awọn iwa rẹ
Awọn origun igbagbọ-ododo“Al-Iimaan” - (Èdè Yorùbá)
No Description
Nini Igbagbọ si Ọjọ Idajọ - 3 - (Èdè Yorùbá)
Ninu apa yii alaye diẹ waye nipa awọn iroyin Alujannah ati Ina, ti ibeere ati idahun si jẹ ohun ti wọn fi kadi idanilẹkọ nilẹ.
Nini Igbagbọ si Ọjọ Idajọ - 2 - (Èdè Yorùbá)
Alaye tẹsiwaju lori awọn isẹlẹ ti yoo sẹlẹ lẹyin iku pẹlu mimẹnuba oniranran ipo ọmọniyan nigbati wọn ba gbe sinu saare.
Nini Igbagbọ si Ọjọ Idajọ - 1 - (Èdè Yorùbá)
Ninu apa yii ọrọ waye lori awọn ẹri lati inu Alukuraani ti o ntọka si ododo sisẹlẹ ọjọ igbende Alukiyaamọ ati bi o se jẹ dandan ki a ni igbagbọ si ọjọ naa, ti olubanisọrọ si sọ diẹ ninu awọn amin isunmọ ọjọ yii pẹlu awon ẹri ti o gbee....
Igbagbo Ninu Kadara - (Èdè Yorùbá)
Ibanisoro yi da lori alaye ni ekunrere nipa ohun ti a n pe ni kadara ati bi awon eniyan kan se sonu nitori re.
Taani Olohun- 2 - (Èdè Yorùbá)
Olubanisọrọ tẹsiwaju ninu alaye awọn nkan ti o maa nse akoba fun Taoheed ninu iran Ẹbọ sise ati okunfa re, gẹgẹ bii Mima se ijọsin nibi saare oku, Gbigbẹ saare si inu mọsalaasi, Tita ẹjẹ silẹ fun nkan miran ti o yatọ si Ọlọhun Allah, Wiwa idaabobo tabi iranlọwọ lọdọ....
Taani Olohun- 1 - (Èdè Yorùbá)
Olubanisọrọ bẹrẹ pẹlu alaye orisirisi awọn alajẹ ede ti awọn eniyan fun Ọlọhun Allah, o si tun se alaye nipa Eni ti o tọ ki a maa jọsin fun laiwa orogun pẹlu Rẹ Ohun naa ni Ọlọhun .O si tun tẹsiwaju ninu sise alaye ohun ti wọn npe ni At-Taoheed....
Ojise Olohun Muhammad Ike ni o je fun Gbogbo Aye - (Èdè Yorùbá)
Olubanisoro se alaye bi ojise Olohun anabi Muhammad se je ike fun gbogbo aye, Olohun lo ojise naa lati se agbega fun awon iwa rere O si loo lati pa awon iwa buburu re. Olohun si da ojise re ni eniti o pe ni eda ati ni iwa.
Igbagbo Ododo - (Èdè Yorùbá)
Ibanisoro yi da lori igbagbo ninu Olohun ati alaye itumo re. Olubanisoro yi se alaye pupo lori itumo ohun ti o nje igbagbo, o si fi awon apeere laakaye ba awon eniyan soro pupo nibe nitoripe eleyi ni o ba awon ogooro eniyan ti won wa ni ijoko naa mu.....
Gbigba Kadara gbo - (Èdè Yorùbá)
Akole yi so nipa bi o ti se je ojuse Musulumi ki o so enu aala Olohun nigba ti o ba n wa arisiki, ki o ma gba ona haraam ti Olohun ko fe lati fi wa oro. Ki o ma fi ibinu Olohun wa iyonu awon eniyan.
No Description