No Description
Alaye bi irun anabi ki ikẸ ati Ọla ỌlỌhun o maa ba a ti ri - (Èdè Yorùbá)
Ola Ti O Nbe Nibi Irun Kiki Ati Awon Anfaani Re - (Èdè Yorùbá)
Oore ti o po pupo ni o wa nibi irun kiki fun Musulumi. Ohun ni ona ti o dara julo lati wa asunmo si odo Olohun, o si maa nse okunfa aforiji fun Musulumi, bakannaa ni o je oluranlowo fun erusin lati wo ogba idera (al-Jannah).
Ipo Irun Ninu Islam - (Èdè Yorùbá)
Akosile yi so nipa bi irun kiki ti se pataki to ninu esin Islam, ohun ni origun ti o lola julo leyin ijeri mejeeji, ohun naa si ni ise ti erusin maa n se ti o loore julo leyin won.
Baa seki Irun - (Èdè Yorùbá)
Baa seki Irun
Awón Inkan Too dan dan ni bii Ikirun - (Èdè Yorùbá)
Awón Inkan Too dan dan ni bii Ikirun
Awón Inkan Too baa Irun kiki jé - (Èdè Yorùbá)
Awón Inkan Too baa Irun kiki jé
Awón Origun tin béni bii Ikirun - (Èdè Yorùbá)
Awón Origun tin béni bii Ikirun
Awón majémuu Ikirun - (Èdè Yorùbá)
Awón majémuu Ikirun
BI ANABI SEN KIRUN IKE OLOHUN ATI OLA OLOHUN KOMA BA - (Èdè Yorùbá)
BI ANABI SEN KIRUN IKE OLOHUN ATI OLA OLOHUN KOMA BA
Pataki Irun Oru (Kiyaamu Laeli) – 3/ 3 - (Èdè Yorùbá)
Awọn Afaani Irun Oru.
Pataki Irun Oru (Kiyaamu Laeli) – 2/ 3 - (Èdè Yorùbá)
Alaye lori awọn nkan ti o yẹ ki Musulumi se ti o ba ji dide loru pẹlu aworan irun orun ni ọdọ awọn Saabe Anabi ati ti awọn ẹniire ti wọn ti siwaju lọ.
Pataki Irun Oru (Kiyaamu Laeli) – 1/ 3 - (Èdè Yorùbá)
Iroyin Irun Oru pẹlu ẹri rẹ lati inu Alukuraani ati Sunnah ati Pataki rẹ