Fun oriire ni aye yi ati ni orun, oranyan ni fun Musulumi ki o mo wipe Al-kurani ati Sunna ni ohun yoo maa seri si fun gbogbo oro esin re. Eleyi si ni isesi awon eni isiwaju lati ori awon Saabe Ojise Olohun ati awon ti won tele ilana won.....
Paapaa Ibẹru Ọlọhun - (Èdè Yorùbá)
Alaye lẹkunrẹrẹ nipa ibẹru Ọlọhun, awọn ẹri rẹ lati inu Alukuraani ati Sunnah pẹlu apejuwe rẹ ni ọdọ awọn ẹni rere.
Itumọ Aye labẹ Agbọye Islam - 2 - (Èdè Yorùbá)
Sise afihan bi eniyan se nifẹ si aye pupọ ati ọrọ nipa awọn nkan ti o jẹ iranlọwọ lati ma si aye lo
Itumọ Aye labẹ Agbọye Islam -1 - (Èdè Yorùbá)
Itumọ Aye labẹ agbọye awọn Aafa ẹsin
Iduro sinsin - (Èdè Yorùbá)
Akori ibanisọrọ da lori wipe iduro sinsin jẹ ẹmi gbogbo awọn isẹ ijọsin patapata. Idahun si awọn ibeere olowo-iye-biye nipa ibanisọrọ ti o waye lori Iduro sinsin.
Awon Arun Okan - (Èdè Yorùbá)
1- Ibanisoro yii se afihan orisi ona meta ti Okan pin si, bee si ni Olubanisoro je ki a mo awon orisi arun ti o ma nse Okan. 2- Alaye ni afikun lori okan ti o nse aare ati ohun ti o je iwosan fun un. Iwosan ti o si....
Atubọtan-3 - (Èdè Yorùbá)
Ni apa yii alaye wa lori okunfa atubọtan daadaa fun eniyan pẹlu awọn apẹẹrẹ ti a o ri lara eniyan, ti njuwe pe iru ẹni bayi ni atubọtan daadaa.
Atubọtan-2 - (Èdè Yorùbá)
Ninu apa yii alaye waye lori awọn iwa tabi isesi ti o maa nfa atubọtan buruku fun eniyan.
Atubọtan-1 - (Èdè Yorùbá)
Alaye itumọ ohun ti a mọ si atubọtan ati awọn isẹ ti o maa nfa atubọtan buruku fun eniyan.
Adanwo: Itumọ rẹ ati bi Musulumi yoo se se pẹlu rẹ 3/ 3 - (Èdè Yorùbá)
Awọn ọna abayọ kuro ninu adanwo.
Awon Iroyin Jije Eni Olohun - (Èdè Yorùbá)
Oniwaasi so wipe awon majemu meta kan wa fun jije eni Olohun (i) Ki eniyan so asepo laarin ara re ati Olohun re (ii) Ki o so asepo laarin oun ati emi ara re (iii) Ki o so asepo laarin oun ati awujo re.
Tituuba nibi Ẹsẹ ati awọn majẹmu rẹ - (Èdè Yorùbá)
Alaye lori awọn majẹmu wiwa tituuba lọsi ọdọ Ọlọhun