×
Image

Awọn Okunfa ti o n da Igbeyawo ru - (Èdè Yorùbá)

Itumọ idile alayọ ati ajọse ti o yẹ ki o wa laarin ọkọ ati iyawo rẹ, pẹlu imọran lori bi o se yẹ ki ọkọ maa se daradara si awọn ara ile rẹ.

Image

Awọn Obirin Ninu Islam - (Èdè Yorùbá)

No Description

Image

Awon leta ti o wa fun awon Alhaji ati awon oni Umrah - (Èdè Yorùbá)

No Description

Image

BI ANABI SEN KIRUN IKE OLOHUN ATI OLA OLOHUN KOMA BA - (Èdè Yorùbá)

BI ANABI SEN KIRUN IKE OLOHUN ATI OLA OLOHUN KOMA BA

Image

Ifeto si Ọmọ Bibi, Ifopin si Ọmọ Bibi, ati Oyun Sisẹ -1 - (Èdè Yorùbá)

Ibanisọrọ yi se alaye awọn koko wọnyi: (1) Iyatọ laarin ifeto sọmọ bibi ati ifopin sọmọ bibi. (2) Awọn ẹri pe Islam se wa lojukokoro lori ọmọ bibi. (3) Itan igba ti irori fifi opin si ọmọ bibi bẹrẹ.

Image

Ifeto si Ọmọ Bibi, Ifopin si Ọmọ Bibi, ati Oyun Sisẹ - 2 - (Èdè Yorùbá)

Ni apa keji yi: (1) Itẹsiwaju alaye lori igbati irori fifi opin si ọmọ bibi bẹrẹ. (2) Ọrọ nipa oyun nini ati awọn idajọ ẹsin ti o rọ mọ ọ

Image

Ifeto si Ọmọ Bibi, Ifopin si Ọmọ Bibi, ati Oyun Sisẹ - 3 - (Èdè Yorùbá)

Eyi ni abala ti o kun fun ibeere ati idahun, ti awọn ọrọ olowo-iye-biye si ti ibẹ yọ.