×
Image

Islaamu ni ẹsin awọn ojiṣẹ Ọlọhun - (Èdè Yorùbá)

Islaamu ni ẹsin awọn ojiṣẹ Ọlọhun

Image

ELÉYÌÍ NII ÌPÌLẸ̀ O DI ỌWỌ RẸ IRẸ ARẸWÀ ILE ADÚLÁWỌ̀ - (Èdè Yorùbá)

ELÉYÌÍ NII ÌPÌLẸ̀ O DI ỌWỌ RẸ IRẸ ARẸWÀ ILE ADÚLÁWỌ̀

Image

Kí ni Kuraani Alapọn-ọnle? - (Èdè Yorùbá)

Kí ni Kuraani Alapọn-ọnle?

Image

ISLAM ESIN GBOGBO OJISE. - (Èdè Yorùbá)

ISLAM ESIN GBOGBO OJISE.

Image

TALODAMI ATIWIPE KINI ATORI E DA MI? - (Èdè Yorùbá)

TALODAMI ATIWIPE KINI ATORI E DA MI?

Image

Tani o da agbaye? Taa si ni o da mi? Ati pe ki ni idi ti o fi da mi? - (Èdè Yorùbá)

Tani o da agbaye? Taa si ni o da mi? Ati pe ki ni idi ti o fi da mi?

Image

Islaamu ni ẹsin Oluwa gbogbo agbaye - (Èdè Yorùbá)

Islaamu ni ẹsin Oluwa gbogbo agbaye

Image

Awon Iroyin Jije Eni Olohun - (Èdè Yorùbá)

Oniwaasi so wipe awon majemu meta kan wa fun jije eni Olohun (i) Ki eniyan so asepo laarin ara re ati Olohun re (ii) Ki o so asepo laarin oun ati emi ara re (iii) Ki o so asepo laarin oun ati awujo re.

Image

Itumo Igberaga - (Èdè Yorùbá)

Alaye ohun ti a n pe ni igberaga ohun naa ni ki eniyan maa se atako ododo ti o fi oju han ati yiyepere awon eniyan miran.

Image

Ikẹ ati Aanu sise ninu Ẹsin Islam - (Èdè Yorùbá)

1- Alaye wa ninu idanilẹkọ yii lori: (1) Itumọ ikẹ ati aanu gẹgẹ bi awọn onimimọ ẹsin se se alaye rẹ. (2) Diẹ ninu awọn agbegbe ti ikẹ ati aanu ti gbodo maa waye gẹgẹ bii ki olori se ikẹ fun awọn ọmọlẹyin rẹ ati sise aanu fun awọn ọmọde.....

Image

Ibẹru Ọlọhun - (Èdè Yorùbá)

Koko idanilẹkọ yii da lori awọn nkan mẹta wọnyii: (i) Ọla ti nbẹ fun ibẹru Ọlọhun, (ii) Pataki ibẹru Ọlọhun, (iii) Anfaani ti o wa nibi bibẹru Ọlọhun.

Image

Aleebu Iwa Igberaga - (Èdè Yorùbá)

Ibanisọrọ yi da lori alaye nipa aleebu ti o wa nibi iwa igberaga ati awọn oore ti o nbẹ nibi itẹriba.