Óró Nipa Ifin tin jè Igbaa gbó odoo doo Nipa Awan Tirara towa lat
Óró Nipa Ifin tin jè Igbaa gbó odoo doo Nipa Awan Malaika mani
Óró Nipa Ifin tin jè Igbaa gbó odoo doo Nipa Ólőhun (Allaah) mani
Islam Awọn ipilẹ rẹ ati awọn ipilẹsẹ ẹkọ rẹ - (Èdè Yorùbá)
No Description
Tani o da agbaye? Taa si ni o da mi? Ati pe ki ni idi ti o fi da mi?
Idajo Islam lori Orin kiko ati Gbigbo - (Èdè Yorùbá)
Waasi yi so nipa idajo Islam lori orin kiko ati gbigbo. Oniwaasi mu awon eri ti o po wa lati inu Al-kurani ati hadiisi lori bi orin gbigbo ati kiko se je eewo ninu Islam. Bakannaa ni oro waye ninu waasi yi lori awon aburu repete ti o wa nibi....
Awon Eko Pataki Nibi Ogun Khandak - (Èdè Yorùbá)
Alaye ohun ti o se okunfa ogun yii ati awon isele ti o waye nibi sise ipalemo fun ogun naa eyi ti o je eri ododo lori wipe Annabi Muhammad ojise Olohun ni. Alaye si tun waye lori aranse ti Olohun se fun ojise Re ninu ogun naa.
Diẹ nipa Itan Anọbi Isa (Ọla Ọlọhun ki o maa ba a) - (Èdè Yorùbá)
1- Alaye waye ni agbegbe yii lori itan ranpẹ nipa ẹni tii se iya-iya Anọbi Isa ati iya rẹ pẹlu alaye nipa bi bibi rẹ se waye. 2- Ọrọ waye ni abala yii nipa awọn isẹ iyanu ti Ọlọhun se lati ọwọ Anọbi Isa. Ibeere si waye wipe se ọmọ....
Idajọ ki Musulumi jẹ Ẹran ti Yahudi ati Nasara ba pa - (Èdè Yorùbá)
Idanilẹkọ ti o se alaye: (1) Idajọ ẹran ti Musulumi ba pa, yala o da orukọ Ọlọhun si ni tabi ko da orukọ Ọlọhun si ni latari igbagbe. (2) Idajọ Ẹran ti Yahudi tabi Nasara ba pa yala fun ọdun ni tabi fun nkan miran. (3) Idajọ gbogbo ẹran ti....
Iroyin Ina ati Awọn ohun ti ngbe Eniyan wọ ọ - (Èdè Yorùbá)
1- Idanilẹkọ ni agbegbe yii sọ awọn ayọka Alukuraani ati ẹgbawa hadisi ti nse apejuwe bi Ina se ri. 2- Alaye awọn okunfa ti o maa nmu eniyan wọ Ina, awọn okunfa yii pin si meji: (1) Okunfa ti o maa nmu eniyan bẹ ninu Ina lọ gbere, (2) okunfa....
Iroyin Alujannah ati Awọn Olugbe rẹ - (Èdè Yorùbá)
1- Idanilẹkọ yii sọ nipa oniranran apejuwe nipa ibugbe Alujannah gẹgẹ bi awọn apejuwe yii se wa lati inu Alukuraani ati Sunnah Ojisẹ Ọlọhun. 2- Alaye lori awọn isẹ ti o maa nse okunfa wiwọ Alujannah gẹgẹ bi Ọlọhun ti se se iroyin rẹ lati inu Alukuraani ati Sunna.
Idanilẹkọ yii da lori awọn Iwa Abiyì ti a le kọ ẹkọ rẹ lati ara Anọbi Muhammad [Ikẹ ati ola Ọlọhun ki o maa ba a]

API



