Awon apo-iwe ti ohun fun kika idamewa igbeyin ninu alukurani alaponle, awon naa ni: eleekeji-din-logbon, eleekokan-din-logbon ati ogbon, pelu itumo re ni ede yoruba pelu ohun ti o dun, ti o wu eti gbo.
Ọla ti nbẹ fun kika Alukurani Alapọnle - (Èdè Yorùbá)
Idanilẹkọ yi sọ nipa ohun ti a npe ni Alukuraani pẹlu awọn ẹri lati inu ayọka rẹ, ọrọ si tun waye lori awọn ọla ti o wa fun kika rẹ ati awọn ẹkọ ti o rọ mọ kike rẹ.
Itumaa Kurani - (Èdè Yorùbá)
Itumaa Kurani
Ibanisoro yi da lori bi o ti je dandan fun Musulumi lati maa tele ilana awon asiwaju ninu esin papaajulo awon omoleyin ojise Olohun (Saabe) ati awon ti won tele won (Taabi’un) nigbati o ba fe mo itumo Alukurani Alaponle.
Alaye Aaya kẹjọ ati ẹkẹsan ninu Suuratul Mumtahinah - (Èdè Yorùbá)
Ohun ti o waye ninu ibanisọrọ yii: (1) Sise daadaa si aladugbo ti kiise Musulumi. (2) Ki ọmọ maa se daadaa si awọn obi rẹ mejeeji ti wọn kiise Musulumi.

API



