×
Image

Ọna ti o tọ lati gbarale Ọlọhun Allah - (Èdè Yorùbá)

Alaye nipa pataki ati igbarale Ọlọhun Allah ati ọna ti awọn eniyan pin si nibi gbigbarale Ọlọhun.

Image

Ibẹru Ọlọhun ninu Irun kiki - (Èdè Yorùbá)

Awọn koko idanilẹkọ yii: (1) Alaye itumọ ibẹru Ọlọhun ninu irun kiki pẹlu apejuwe rẹ nibi isesi awọn ẹni-isaaju ti wọn jẹ ẹni-rere. (2) Itaniji si awọn isesi kan ti ko lẹtọ ninu irun. (3) Awọn ohun ti o le se okunfa ibẹru Ọlọhun ninu irun.