Ibanisoro yi so nipa die ninu awon apeere ti a o fi maa mo nigbati opin aye ba n sunmo. Oniwaasi so ni ibere oro yi wipe gbigbe dide Anabi wa Muhammad je okan ninu awon apeere irole aye. Bakannaa ni oro wa lori sisokale Anabi Isa omo Maryam gege....
Amin Irole Aye - 1 - (Èdè Yorùbá)
Ninu Apẹẹrẹ Opin Aye Ẹranko Nla ti yoo jade - (Èdè Yorùbá)
Idanilẹkọ yii jẹ ki a mọ Iru ẹranko, igba ati wipe ibo ni ẹranko naa yoo ti jade ni opin aye
Ninu Apẹẹrẹ Opin Aye ni Eefin ti yoo jade - (Èdè Yorùbá)
Alaye lori eefin nla kan ti yoo bo aye kan pẹlu aburu eefin naa.
Ninu Apẹẹrẹ Opin Aye Jijade Yaajuuj ati Maajuuj - (Èdè Yorùbá)
Sise apejuwe aburu yaajuuja ati maajuuja pẹlu ẹri lori rẹ lati inu Alukuraani ati Sunnah.
Apejuwe bi Anabi Isa [Ọla Ọlọhun ki o maa ba a] yoo se sọkalẹ nigbati aye ba n lọ si opin pẹlu ẹri rẹ lati inu Alukuraani, ẹgbawa hadisi ati ọrọ awọn aafa onimimọ.
Ọna Abayọ lọwọ Aburu Masiihu Dajjaal - (Èdè Yorùbá)
Idanilẹko yii kun kẹkẹ fun awọn ọna abayọ kuro nibi aburu Masiihu Dajjaal
Ninu Awọn Apẹẹrẹ Ọjọ Ikẹhin - Jijade Masiihu Dajjaal - (Èdè Yorùbá)
1 - Ọrọ nipa Masiihu Dajjaal gẹgẹ bi Ojisẹ Olọhun [Ikẹ ati ọla Ọlọhun ki o maa ba a] ti se apejuwe ati awọn iroyin rẹ fun wa. 2 - Agbegbe yii pese idahun si awọn ibeere yii: Se Masiihu Dajjaal nsẹmi lọwọ lọwọ, Njẹ yoo bimọ, ilu wo ni....
Ninu Awọn Apẹẹrẹ Ọjọ Ikẹhin - Jijade Mahdi - (Èdè Yorùbá)
Ẹkunrẹrẹ alaye lori awọn orukọ pẹlu awọn iroyin Mahdi naa
Awọn Amin Opin Aye - (Èdè Yorùbá)
(i) Awọn orukọ ti Ọjọ Ikẹhin njẹ, (ii) Igba ti aye yoo parẹ, ati wipe bawo ni o se sunmọ tabi jinna to.
Iroyin Alujannah ati Awọn Olugbe rẹ - (Èdè Yorùbá)
1- Idanilẹkọ yii sọ nipa oniranran apejuwe nipa ibugbe Alujannah gẹgẹ bi awọn apejuwe yii se wa lati inu Alukuraani ati Sunnah Ojisẹ Ọlọhun. 2- Alaye lori awọn isẹ ti o maa nse okunfa wiwọ Alujannah gẹgẹ bi Ọlọhun ti se se iroyin rẹ lati inu Alukuraani ati Sunna.
Iroyin Ina ati Awọn ohun ti ngbe Eniyan wọ ọ - (Èdè Yorùbá)
1- Idanilẹkọ ni agbegbe yii sọ awọn ayọka Alukuraani ati ẹgbawa hadisi ti nse apejuwe bi Ina se ri. 2- Alaye awọn okunfa ti o maa nmu eniyan wọ Ina, awọn okunfa yii pin si meji: (1) Okunfa ti o maa nmu eniyan bẹ ninu Ina lọ gbere, (2) okunfa....