×
Image

Awón Majemuu Sise Aluwala - (Èdè Yorùbá)

Awón Majemuu Sise Aluwala

Image

Awon Idajo Esin Nipa Aja Ati Egbin re - (Èdè Yorùbá)

Idanileko yi je alaye nipa hadiisi eleekefa ninu tira “Umdatul Ahkaam”. Oludanileko so nipa egbin aja ati awon idajo ti o ro mo o, o si tun so nipa awon agbegbe ti esin ti gba awa Musulumi laaye lati se anfaani lara aja gege bii fifi so ile ati beebee....

Image

Alaye Hadiisi Nipa Idajo Nkan Osu Obinrin Ninu Tira Umdatul Ahkaam - (Èdè Yorùbá)

Eyi ni alaye awon Haadisi tinso nipa Eje Nkan Osu Obinrin lati inu tira ‘Umudatul Haakaam’, ti olubanisoro si s’alaye awon idajo esin ti o ro mo.

Image

Alaye Awon Hadiisi nipa Imora Oniyagbe (Tayammum) ninu Tira Buluugul-maroom - (Èdè Yorùbá)

Alaye nipa imora oniyagbe (imora ti kosi omi nibe) ati awon idajo esin ti o so mo o.

Image

Awọn Ekọ ti o rọ mọ sise Igbansẹ (Itọ ati Igbẹ) - (Èdè Yorùbá)

Alaye lori awọn ekọ ati awọn ohun ti o je dandan fun musulumi lati se nigbati o ba fẹ se igbansẹ, ọrọ si tun waye lori awọn aaye ti a kọ fun ni lati se igbansẹ si.

Image

Aluwala Oniyagbẹ (At-Tayammum) - (Èdè Yorùbá)

Idanilẹkọ yii da lori idajọ aluwala oniyagbẹ (at-tayammum), ati wipe nigba wo ni a le se e ati bi a se nse e.

Image

Baa sese Aluwala Tan manfi Eepe se - (Èdè Yorùbá)

Baa sese Aluwala Tan manfi Eepe se

Image

Idajo ki eniyan to ni iduro - (Èdè Yorùbá)

Fatwa yi so fun wa nipa bi o ti je wipe eniyan leto lati to ni iduro bi o tile je wipe ipile ni ki eniyan bere nigbati o ba fe to.