Alaye waye ninu waasi yi nipa bi Ojise Olohun- ike ati ola Olohun ki o maa ba a- ti se ki irun bi osan ba di oru ni oju aye re pelu awon idajo irun yii. Oro si tun waye lori wipe oorun ati osupa ninu awon amin agbara Olohun....
Idajọ Irun ti a fi n wa Ojo (Sọlaatul-istiskaai) - (Èdè Yorùbá)
Eyi ni ẹkunrẹrẹ alaye lori bi Ojise Olohun- ike ati ola Olohun ki o maa ba a- se maa n ki Irun Itọrọ Ojo pẹlu sise afihan awọn orisirisi ọna ti o gba se adua lati tọrọ ojo nigba aye rẹ.
Alaye nipa Irun Odun Mejeeji ninu tira Buluugul-maraam - (Èdè Yorùbá)
1- Alaye lori Irun Ọdun mejeeji ati awọn ofin ti o rọ mọ aaye ikirun pẹlu awọn imura ti wọn fẹ ki a mu fun Irun ọdun. 3- Idanileko ni apa yi da lori awọn ẹwa khutuba Ojise Olohun- ike ati ola Olohun ki o maa ba a- ni ọjọ....
Iforikanlẹ Itanran Igbagbe lori Irun - (Èdè Yorùbá)
Awọn koko Idanilẹkọ yi: (i) Awọn ohun mẹta ti o maa nse okunfa iforikanlẹ itanran igbagbe lori Irun. (ii) Awọn aaye ti a ti maa nse iforikanlẹ itanran igbagbe, siwaju salamọ ni tabi lẹyin salamọ. (iii) Awọn idajọ ti o rọ mọ iforikanlẹ itanran igbagbe.
Asigbọ lori Akoko Irun Jimọh - (Èdè Yorùbá)
Idanilẹkọ yii se alaye ọrọ awọn onimimọ ti o da lori igba ti o yẹ ki a maa ki Irun Jimọh, ni idahun si asigbọye ẹsin eyi ti o n waye lati ọwọ ikọ awọn ọdọ Musulumi kan ti wọn ngbe Irun Jimọh duro ni aago mẹsan awurọ.
Awọn Aisedeede ti o maa nsẹlẹ pupọ lori Irun - (Èdè Yorùbá)
Pataki irun kiki ati wipe ohun ni akọkọ ohun ti Musulumi yoo se isiro rẹ ni ọjọ ajinde. Diẹ ninu awọn aisedeede naa gẹgẹ bii: aifarabalẹ, wiwo ọtun wosi lori irun ati bẹẹbẹẹ lọ.
Ibẹru Ọlọhun ninu Irun kiki - (Èdè Yorùbá)
Awọn koko idanilẹkọ yii: (1) Alaye itumọ ibẹru Ọlọhun ninu irun kiki pẹlu apejuwe rẹ nibi isesi awọn ẹni-isaaju ti wọn jẹ ẹni-rere. (2) Itaniji si awọn isesi kan ti ko lẹtọ ninu irun. (3) Awọn ohun ti o le se okunfa ibẹru Ọlọhun ninu irun.
Igberun Duro - (Èdè Yorùbá)
Igberun Duro
Pataki Irun Oru (Kiyaamu Laeli) – 1/ 3 - (Èdè Yorùbá)
Iroyin Irun Oru pẹlu ẹri rẹ lati inu Alukuraani ati Sunnah ati Pataki rẹ
Pataki Irun Oru (Kiyaamu Laeli) – 2/ 3 - (Èdè Yorùbá)
Alaye lori awọn nkan ti o yẹ ki Musulumi se ti o ba ji dide loru pẹlu aworan irun orun ni ọdọ awọn Saabe Anabi ati ti awọn ẹniire ti wọn ti siwaju lọ.
Pataki Irun Oru (Kiyaamu Laeli) – 3/ 3 - (Èdè Yorùbá)
Awọn Afaani Irun Oru.
BI ANABI SEN KIRUN IKE OLOHUN ATI OLA OLOHUN KOMA BA - (Èdè Yorùbá)
BI ANABI SEN KIRUN IKE OLOHUN ATI OLA OLOHUN KOMA BA

API



