Idanilẹkọ yii da lori awọn ọna ti musulumi fi le wa isọ Ọlọhun ati aabo Rẹ gẹgẹ bii: Jijẹ eso dabidun ‘ajiwa, sise aluwala loore koore, mima ki irun Fajri ni jama’a, mima ki irun oru, ati bẹẹ bẹẹ lọ.
Awọn Ọna ti o ba Ẹsin Islam mu fun Isọ Ọlọhun ati Aabo Rẹ - (Èdè Yorùbá)
Awọn ohun ti kii jẹ ki Adua o gba - (Èdè Yorùbá)
Akosile ti o da lori awon nkan ti apa kan ninu awon Musulumi maa n se ti o maa n se okunfa ki Olohun ma gba adua won
Kinni o maa n jẹ ki Adua gba? - (Èdè Yorùbá)
Akọsilẹ ti o kun fun anfaani nipa awọn okunfa gbigba adua fun Musulumi ododo pẹlu awọn ẹri lati inu Alukuraani ati Sunna.
Akọsilẹ yii sọ diẹ ninu awọn asise ti apa kan ninu awọn Musulumi maa n se nibi iranti Ọlọhun, gẹgẹ bii kikojọ se iranti Ọlọhun, fifi asiko tabi onka si iranti Ọlọhun eyi ti kosi ninu Shẹria Islam.
Pataki Iranti Ọlọhun - (Èdè Yorùbá)
Akọsilẹ ti o sọ nipa pataki iranti Ọlọhun pẹlu awọn ẹri lati inu Alukurani ati hadiisi.
Adua ati Asikiri - (Èdè Yorùbá)
1- Itumọ adua ati asikiri lati inu agbọye Alukuraani ati Sunnah pẹlu alaye lori ẹkọ adua ati asikiri ni sise. 2- Pataki adua, asiko gbigba adua ati gbogbo ohun ti o takọ ilana gbigbaa adua ni sise.