Ibanisọrọ yi da lori alaye nipa aleebu ti o wa nibi iwa igberaga ati awọn oore ti o nbẹ nibi itẹriba.
Aleebu Iwa Igberaga - (Èdè Yorùbá)
Suuru ati erenje ti o nbẹ fun un - (Èdè Yorùbá)
Ninu idanilẹkọ yii: (1) Pataki suuru sise. (2) Ọna maarun ti suuru pin si. (3) Ẹsan rere ti nbẹ nibi suuru sise.
Tituuba nibi Ẹsẹ ati awọn majẹmu rẹ - (Èdè Yorùbá)
Alaye lori awọn majẹmu wiwa tituuba lọsi ọdọ Ọlọhun
Pataki Didu Ọpẹ fun Ọlọhun Allah ati awọn Anfaani rẹ - (Èdè Yorùbá)
Agbọye didu ọpẹ fun Ọlọhun Allah, ati awọn anfaani ati ọla ti n bẹ fun ọpẹ didu.
Awon Iroyin Jije Eni Olohun - (Èdè Yorùbá)
Oniwaasi so wipe awon majemu meta kan wa fun jije eni Olohun (i) Ki eniyan so asepo laarin ara re ati Olohun re (ii) Ki o so asepo laarin oun ati emi ara re (iii) Ki o so asepo laarin oun ati awujo re.
Itumọ Gbigbarale Ọlọhun ati awon Asise ti o n sẹlẹ nibẹ - (Èdè Yorùbá)
Itumọ Gbigbarale Ọlọhun pẹlu ẹri rẹ lati inu Alukuraani ati Sunnah ati wipe se gbigbarale Ọlọhun tumọ si aajo sise?
Adanwo: Itumọ rẹ ati bi Musulumi yoo se se pẹlu rẹ 1/ 3 - (Èdè Yorùbá)
Itumọ adanwo ati orisirisi awọn aworan ti o maa ngba kan ọmọ’niyan.
IRIN AJO TI KO SE YE (IRIN AJO IKU) - (Èdè Yorùbá)
Oro nipa iku ati bi a se n we oku ni ilana esin Islam, pelu itoka si die ninu awon ohun ti o je dandan ki Musulumi ni igbagbo si lehin iku.
Adanwo: Itumọ rẹ ati bi Musulumi yoo se se pẹlu rẹ 3/ 3 - (Èdè Yorùbá)
Awọn ọna abayọ kuro ninu adanwo.
Adanwo: Itumọ rẹ ati bi Musulumi yoo se se pẹlu rẹ 2/ 3 - (Èdè Yorùbá)
Adanwo ti o ba awọn Anọbi Ọlọhun, anfaani ti o wa nibi ki Ọlọhun fi adanwo kan Musulumi ati Okunfa adanwo.
Ọna ti A le gba ri Owo ati Ọna nina rẹ ninu Islam - 1/ 3 - (Èdè Yorùbá)
Pataki owo ati wipe wiwa owo gbọdọ jẹ lati ọna ti o mọ ti o si jẹ ẹtọ
Ọna ti A le gba ri Owo ati Ọna nina rẹ ninu Islam - 2/ 3 - (Èdè Yorùbá)
Awọn ọna ti a le gba ko arisiki jọ pẹlu awọn ẹri wọn lati inu Alukuraani ati Sunnah.