1- Alaye lori Irun Ọdun mejeeji ati awọn ofin ti o rọ mọ aaye ikirun pẹlu awọn imura ti wọn fẹ ki a mu fun Irun ọdun. 3- Idanileko ni apa yi da lori awọn ẹwa khutuba Ojise Olohun- ike ati ola Olohun ki o maa ba a- ni ọjọ....
Alaye nipa Irun Odun Mejeeji ninu tira Buluugul-maraam - (Èdè Yorùbá)
Gbigba Aawe Ninu Gbogbo Awon Ojo Osu Rajab Ati Sha’baan - (Èdè Yorùbá)
Awon eniyan kan maa n gba aawe ninu gbogbo ojo osu Rajab at Sha’baan lehinnaa Ramadan, nje eri wa lori ohun ti won n se yi bi?
Eko nipa Odun Itunu Aawe - (Èdè Yorùbá)
Olohun se ipari aawe ati ojo kewa osu Dhul-hijja ni odun fun awa Musulumi. Ibani soro yi n so nipa awon eko ti Islam ko wa nipa odun aawe. Ninu re ni ki Musulumi wo aso ti o dara ti o si wuyi ni ojo odun lati gbe ojo yi....
Igbaradi fun Osu Awe Ramadan - 1 - (Èdè Yorùbá)
Khutba yi so nipa bi Musulumi yoo se mura sile fun osu Ramadan lati gba aawe nibe ati lati se awon naafila nibe. O so nipa bi awon eni isiwaju ninu esin se maa n pade osu Ramadan pelu idunnu ati ayo, ti won si maa n banuje ti o....
Igbaradi fun Osu Awe Ramadan - 2 - (Èdè Yorùbá)
Khutba yi so nipa oore ti o po ti Olohun se fun awa Musulumi pelu bi O ti se awon asiko kan ni adayanri fun awon ise oloore ti Musulumi yoo maa gba esan ti o po lori won. Ninu awon asiko naa si ni ojo Jimoh ati idameta oru....
Ola Osu Ramadan ati Ilana ti o to lori bibere Aawe nibe - (Èdè Yorùbá)
Ibanisoro yi se alaye ni ekunrere awon ola ti o n be fun osu Ramadan, ninu re si ni wipe Olohun daruko osu yi ninu Al-kurani ti ko si daruko osu miran leyin re. Ninu awon ola ti Olohun se fun osu yi ni wipe Olohun yoo pa ase wipe....
IDAJỌ GBIGBA AAWẸ OSU RAJAB - (Èdè Yorùbá)
Idajo gbigba aawe ninu osu Rajab bi apa kan ninu awon eniyan se maa n se pelu ero wipe osu naa da yato, awon onimimo si ti se alaye wipe adadaale ni gbogbo awon nkan wonyi.
AWỌN ADADAALẸ INU OSU RAJAB - (Èdè Yorùbá)
Idahun si ibeere nipa wipe irun ti won n pe ni "solaatur-rogaaibi" ati sise adayanri ojo ketadinlogbon ninu osu Rajab fun awon ijosin kan, se awon nkan wonyi ni ipile ninu esin, idahun si waye wipe adadaale ni gbogbo re je.
Idajọ Nafila ni Ọjọ Alaruba ti o kẹhin ninu Osu Safar - (Èdè Yorùbá)
Idajo esin lori yiyan nafila ni ojo alaruba ti o kehin ninu osu Safar ati idajo esin lori wipe irufe nafila bee adadasile ninu esin ni.
Ọrọ Nipa Osu Rajab - (Èdè Yorùbá)
Alaye nipa awọn ohun ti o sẹlẹ ninu osu Rajab gẹgẹ bii osu ọwọ ati awọn osu ọwọ yoku.

API



