Itumọ iwa olojumeji (Nifaak) pẹlu idajọ rẹ ninu ofin Shariah, ati wipe iyatọ wo ni nbẹ ninu ọna meji ti Nifaak pin si.
Iwa Olojumeji ( Nifaak ) - (Èdè Yorùbá)
Igberun Duro - (Èdè Yorùbá)
Igberun Duro
Ẹsin Agbelebu -Christianity- lpilẹ rẹ ati bi o ti da - (Èdè Yorùbá)
Ẹsin Agbelebu -Christianity- lpilẹ rẹ ati bi o ti da
Amin Irole Aye - 1 - (Èdè Yorùbá)
Ibanisoro yi so nipa die ninu awon apeere ti a o fi maa mo nigbati opin aye ba n sunmo. Oniwaasi so ni ibere oro yi wipe gbigbe dide Anabi wa Muhammad je okan ninu awon apeere irole aye. Bakannaa ni oro wa lori sisokale Anabi Isa omo Maryam gege....
Amin Irole Aye - 2 - (Èdè Yorùbá)
Oniwaasi so ninu ibanisoro yi nipa awon apeere kekere ninu awon apeere irole aye, o si menu ba bi o se je wipe awon ti won je onimimo nipa oro Olohun yoo tan ni ori ile, ti iwa agbere yoo po, bakannaa ni oti mimu ati beebeelo.
Amin Irole Aye - 3 - (Èdè Yorùbá)
Oniwaasi so ninu ibanisoro yi nipa awon apeere kekere ninu awon apeere irole aye, o so nipa bi onka awon obinrin yoo se po ni awujo, bakannaa ni ki awon eniyan maa se afiti nkan si odo eni ti kii se eni ti o leto si i.
Amin Irole Aye - 4 - (Èdè Yorùbá)
Oniwaasi so ninu ibanisoro yi nipa awon apeere kekere ninu awon apeere irole aye, o so nipa wiwa imo nitori oro aye, ati bi okunrin yoo se maa tele ase iyawo re ti yoo si maa se aburu si iya re, bakannaa bi awon eniyan yoo se maa pariwo ninu....
Amin Irole Aye - 5 - (Èdè Yorùbá)
Oniwaasi so ninu ibanisoro yi nipa awon apeere kekere ninu awon apeere irole aye, gege bii ki awon eniyan maa se aponle okunrin kan nitori iberu aburu ise owo re. Leyinnaa o menu ba die ninu awon apeere irole aye ti o tobi, o si ka hadiisi ti Udhaefa gba....
Amin Irole Aye - 6 - (Èdè Yorùbá)
Oniwaasi soro nipa eranko kan ti Olohun yoo mu jade si awon eniyan ti yoo si maa ba awon eniyan soro gege bii okan ninu awon apeere irole aye ti o tobi. Bakannaa ni o so nipa yiyo oorun nibi ibuwo re, o si se afikun wipe ni asiko yi....
Amin Irole Aye - 7 - (Èdè Yorùbá)
Oniwaasi soro nipa sisokale Anabi Isa omo Maryam, nigbati o ba de yoo pa agbelebu ati elede run, yoo si maa se idajo pelu deede ni ilana Anabi wa Muhammad.
Amin Irole Aye - 8 - (Èdè Yorùbá)
Oniwaasi soro ni ipari waasi yi o si gba awon Musulumi ni iyanju lori ki won maa moju to esin Olohun bi o ti wule ki ibaje po to ni awujo, ki won si maa be Olohun ni opolopo, ki won jinna si ebo ati awon elebo. O si se....
Oro Nipa Awon Alujannu - 1 - (Èdè Yorùbá)
Alaye ni ekunrere wa ninu ibanisoro yi nipa awon al-jannu. Bibe awon al-jannu ninu imo ikoko ti Musulumi gbodo ni igbagbo si ni, o nbe ninu awon al-jannu yi onigbagbo ododo o si nbe ninu won eni ti o ko ti Olohun ti o je keferi. Olubanisoro tun toka awon....

API



