Awón Inkan Too baa Irun kiki jé
Awón Inkan Too baa Irun kiki jé - (Èdè Yorùbá)
Awón Ton baa Aluwala jé - (Èdè Yorùbá)
Awón Ton baa Aluwala jé
Awón Inkan Too dan dan ni bii Ikirun - (Èdè Yorùbá)
Awón Inkan Too dan dan ni bii Ikirun
Agboye Esin Islam - (Èdè Yorùbá)
Ibanisoro yi so nipa bi esin Islam se je esin ti o dasi igbesi aye eniyan patapata ti kii se nipa ohun ti o nse ninu mosalaasi nikan. Olubanisoro si menu ba itumo Islam, beenaani o so ewu ti o nbe nibi ki eniyan maa tele awon eniyan kan lori....
Oniwaasi so wipe awon nkan itoju arun ti Olohun se fun awa Musulumi po pupo ju ki a maa wa iranlowo nibi ohun ti o wa lodo awon keeferi ati elebo lo. O si so die ninu awon nkan iwosan naa, gege bi o ti so nipa awon eyi ti....
Lilo Sunna Laarin Aseju ati Aseeto Lodo Awon Odo - (Èdè Yorùbá)
Ibanisọrọ yii da lori sise aseju tabi aseeto ninu ẹsin eyi ti o wọpọ laarin awọn ọdọ, ti olubanisọrọ si jẹ ki a mọ awọn okunfa rẹ gẹgẹ bii: 1-Aini imọ ẹsin ti o kun to, 2-Agbọye odi lori ẹsin, 3-lilero aburu si awọn onimimọ, 4-Igbarata ẹsin, 5- Sisọ gbogbo....
Ojuse Asiwaju Si Awọn Ọmọlẹyin - (Èdè Yorùbá)
Alaye bi ẹsin Islam se pa asiwaju ni asẹ lati maa se ojuse rẹ lori awọn ọmọlẹyin rẹ, pẹlu apejuwe igbesi aye saabe agba Umar bin Khataab [Ki Ọlọhun Kẹ ẹ]
Iyatọ laarin Oogun ti o ba Islam mu ati Idan - 1 - (Èdè Yorùbá)
Alaye idajọ Islam lori oogun iwosan – ewe ati egbo ati awọn nkan miran ti o jẹ iwosan fun ọmọniyan.
Iyatọ laarin Oogun ti o ba Islam mu ati Idan - 2 - (Èdè Yorùbá)
Alaye lẹkunrẹrẹ lori idajọ oogun ti o ni ẹbọ ninu pẹlu awọn apẹẹrẹ rẹ.
Iyatọ laarin Oogun ti o ba Islam mu ati Idan - 3 - (Èdè Yorùbá)
Idajọ ẹni ti o n se oogun ẹbọ ni wọn se alaye rẹ ni abala yii.
Awọn Isẹ oloore ti Sharia pa lasẹ ninu Osu Oju Ọrun ati Adadasilẹ ti awọn Eniyan nse nibẹ 3 - (Èdè Yorùbá)
Adadaalẹ ti o ma nwaye nibi isẹ hajj sise, ti idahun si ibeere si jẹ ohun ti o tẹlee.
Imọra Idajọ rẹ ati Ọna ti o pin si - 3 - (Èdè Yorùbá)
Abala yii jẹ abala idahun si ibeere ọlọkan-ọ-jọkan.

API

