×
Image

Ojuse Imam ninu Islam - 3 - (Èdè Yorùbá)

Apa keta ibanisoro naa so nipa idajo kiko masalaasi, bakannaa ni oro waye lori ohun ti o leto ki a se ninu mosalaasi ati awon ohun ti ko leto, leyinnaa ni idahun waye si awon ibeere.

Image

Idajọ Ibura laarin ọkọ ati iyawo (Al-Li’aanu) - (Èdè Yorùbá)

Ibanisọrọ yii da lori igbesẹ ti Islam fẹ ki Ọkọ iyawo gbe ti o ba se akiyesi pe iyawo rẹ nrin irinkurin, ti o si tun nse afihan bi Islam ti se idaabobo fun awọn obinrin kuro nibi abuku irọ Sina.

Image

Idẹkun Wahala laarin Lọkọ-Laya -1 - (Èdè Yorùbá)

Alaye ni abala akọkọ Idanilẹkọ yii da lori awọn koko wọnyii: (i) Sisọ nipa pataki ati anfaani ti o wa nibi igbeyawo, (ii) Sise alaye awọn ojuse lati ọdọ ọkọ si iyawo rẹ, bẹẹ naa ni awọn ojuse lati ọdọ iyawo si ọkọ rẹ, (iii) Sise apejuwe oniranran ede-aiyede laarin....

Image

Idẹkun Wahala laarin Lọkọ-Laya -2 - (Èdè Yorùbá)

Abala yii sọ nipa awọn ọna mẹrin ti ede-aiyede ma ngba wa laarin lọkọ-laya, oludanilẹkọ si tun se alaye awọn igbesẹ ti Islam fẹ ki a gbe nigbati ede-aiyede ba waye laarin lọkọ-laya.

Image

Idẹkun Wahala laarin Lọkọ-Laya -3 - (Èdè Yorùbá)

Eyi ni abala idahun si awọn ibeere ti o jẹyọ lati ibi idanilẹkọ yii.

Image

Ojuse ati Ẹtọ Awọn Obinrin Musulumi ni Awujọ -1 - (Èdè Yorùbá)

Idanilẹkọ yii da lori awọn koko wọnyii: (i) Sise alaye ipo ti awujọ gbe obinrin si pẹlu afiwe rẹ si ipo ti Islam gbe obinrin si. (ii) Sise ni alaye abala diẹ ninu awọn ojuse obinrin musulumi si gbogbo awọn agbegbe ti o nii se pẹlu igbesi aye won.

Image

Ojuse ati Ẹtọ Awọn Obinrin Musulumi ni Awujọ -2 - (Èdè Yorùbá)

Eleyi ni afikun alaye lori awọn ojuse obinrin musulumi, ti alaye nipa awọn ẹtọ obinrin musulumi si jẹ ohun ti wọn fi tẹle.

Image

Awọn Okunfa Igbesi Aye Idunnu fun Lọkọ-laya-1 - (Èdè Yorùbá)

Idanilẹkọ yii da lori itumọ lọkọ-laya ati alaye awọn ohun ti o maa njẹ ki igbesi aye lọkọ-laye ni itumọ gẹgẹ bii: Ibẹru Ọlọhun Allah, Sise akiyesi adehun ti ọkunrin maa nse fun obirin nigba ti wọn ko tii gbe ara wọn wọ ile.

Image

Awọn Okunfa Igbesi Aye Idunnu fun Lọkọ-laya-2 - (Èdè Yorùbá)

Abala yii jẹ alekun alaye lori awọn ohun ti o maa nmu igbesi aye lọkọ-laya ni itumọ ati idahun si awọn ibeere ti o waye.

Image

Ọrọ Nipa Hijaab fun Obinrin Musulumi - 1/ 4 - (Èdè Yorùbá)

A o gbọ ninu Idanilẹkọ yii nipa ipo ti Islam to obinrin si ati apọnle ti Ọlọhun se fun wọn bakannaa kinni itumọ hijaab, idi ti hijaab fi jẹ ọranyan, awọn inira ti nbẹ nibi sisi ara silẹ ati aburu sise agbere.

Image

Ọrọ Nipa Hijaab fun Obinrin Musulumi - 2/ 4 - (Èdè Yorùbá)

Awọn ẹri lati inu Alukuraani ati Sunah lori wipe ọranyan ni Jẹlbaab lilo, apejuwe bi o se yẹ ki Jẹlbaab ri ati majẹmu rẹ.

Image

Ọrọ Nipa Hijaab fun Obinrin Musulumi - 3/ 4 - (Èdè Yorùbá)

Alekun alaye lori majẹmu ati apejuwe bi o se yẹ ki Hijaab ri