1- Ibanisoro yii da lori awon ona abayo si asigbo esin ti o gbaye kan laarin awon Musulumi. 2- Ibanisoro je afikun lori awon okunfa ati ona abayo si awon asigbo tabi aseju ninu esin.
Itosona Lori Asigbo Esin - (Èdè Yorùbá)
Alaye nipa Irun Jimoh ninu tira Buluugul-maraam - (Èdè Yorùbá)
2- Alaye lori awon idajo ti o sopo mo irun Jimoh, ninu won ni: (1) Asiko wo ni irun Jimoh maa n wole. (2) Onka wo ni o ye ki o pe ki a to le ki irun Jimoh. (3) Rakah melo ni Musulumi gbodo ba ki o to le....
Bi a ti se nwẹ Iwẹ Ọranyan (Al-Guslu) - (Èdè Yorùbá)
Ọrọ waye lori awọn nkan marun ti o maa nsọ iwẹ di dandan fun ni lati wẹ, alaye si tun waye ni soki lori bi a se le wẹ iwẹ naa.
Ọla ti o nbẹ fun Aluwala ati bi a ti se nse e - (Èdè Yorùbá)
Idanilẹkọ yii da lori alaye bi a se nse aluwala ati awọn ẹsan (ọla) ti o nbẹ fun aluwala sise, bakannaa ọrọ nipa awọn ohun ti o nsọ aluwala di ọranyan fun musulumi.
Ọranyan Aluwala ati Ohun ti o nba a jẹ - (Èdè Yorùbá)
Alaye nipa awọn ọranyan aluwala, ati awọn ohun ti a fẹ ki Musulumi se ninu aluwala ati awọn ohun ti o nba aluwala jẹ.
Ẹbọ sise: Itumọ rẹ ati Awọn Ipin rẹ - (Èdè Yorùbá)
Idanilẹkọ yi da lori wipe idakeji ẹbọ sise ni sise Ọlọhun Allah ni aaso tabi gbigba A ni okan soso pẹlu ẹri Alukuraani ati ẹgbawa hadisi. Alaye tẹsiwaju nipa itumọ ẹbọ sise pẹlu awọn ọna ti ẹbọ sise pin si.
Ọranyan titẹle Asẹ Ọlọhun Allah ati Asẹ Ojisẹ - (Èdè Yorùbá)
Idanilẹkọ yi da lori wipe titẹle asẹ Ọlọhun ati asẹ Ojisẹ Rẹ (ike ati ola Ọlọhun ki o maa ba a) ni ojulowo ẹsin. Alaye si tun waye nipa wipe sise ọjọ ibi Anọbi (Maoludi Nabiyi) ko ba ofin ẹsin Islam mu pelu awọn ẹri.
Atẹgun sise lọ si ọdọ Ọlọhun Allah - (Èdè Yorùbá)
Koko ibanisọrọ yii ni: (i) Itumọ atẹgun sise lọ si ọdọ Ọlọhun (ii) Awọn ọna ti a ngba se atẹgun lati wa oore ni ọdọ Ọlọhun. (iii) Awọn gbolohun ti o lẹtọ ti Musulumi fi le se atẹgun lọ si ọdọ Ọlọhun.
Ojuse awa Musulumi si Anabi wa Muhammad [Ikẹ ati ọla Ọlọhun ki o maa ba a] da lori awọn koko wọnyii: 1. Titẹle asẹ rẹ. 2. Gbigba ọrọ rẹ gbọ ni ododo. 3. Kikọse rẹ ninu iwa, ẹsin ati isesi. 4. Ninifẹ rẹ pẹlu mimaa se asalaatu fun un, ati....
Isẹ Ijọsin, pataki ati majẹmu rẹ - (Èdè Yorùbá)
Itumọ ijọsin, awọn majẹmu ati erenjẹ ti o wa nibi sise e, ati wipe nitori kini a se nse ijọsin.
Alaye Suratul Fatiha - (Èdè Yorùbá)
Eyi ni alaye Suratul Fatiha lati Aayah akoko titi de Aayah keta pelu awon eko l’oniranran.
Itumọ Adiọkan Musulumi - (Èdè Yorùbá)
Itumọ adiọkan Musulumi ati awọn ẹsan ti n bẹ fun adiọkan ti o ni alaafia ati eyi ti ko ni alaafia

API

