Óró Nipa Ifin tin jè Igbaa gbó odoo doo Nipa Awan Malaika mani
Óró Nipa Ifin tin jè Igbaa gbó odoo doo Nipa Ólőhun (Allaah) mani
Tani o da agbaye? Taa si ni o da mi? Ati pe ki ni idi ti o fi da mi?
Awon Eko Pataki Nibi Ogun Khandak - (Èdè Yorùbá)
Alaye ohun ti o se okunfa ogun yii ati awon isele ti o waye nibi sise ipalemo fun ogun naa eyi ti o je eri ododo lori wipe Annabi Muhammad ojise Olohun ni. Alaye si tun waye lori aranse ti Olohun se fun ojise Re ninu ogun naa.
Diẹ nipa Itan Anọbi Isa (Ọla Ọlọhun ki o maa ba a) - (Èdè Yorùbá)
1- Alaye waye ni agbegbe yii lori itan ranpẹ nipa ẹni tii se iya-iya Anọbi Isa ati iya rẹ pẹlu alaye nipa bi bibi rẹ se waye. 2- Ọrọ waye ni abala yii nipa awọn isẹ iyanu ti Ọlọhun se lati ọwọ Anọbi Isa. Ibeere si waye wipe se ọmọ....
Iroyin Ina ati Awọn ohun ti ngbe Eniyan wọ ọ - (Èdè Yorùbá)
1- Idanilẹkọ ni agbegbe yii sọ awọn ayọka Alukuraani ati ẹgbawa hadisi ti nse apejuwe bi Ina se ri. 2- Alaye awọn okunfa ti o maa nmu eniyan wọ Ina, awọn okunfa yii pin si meji: (1) Okunfa ti o maa nmu eniyan bẹ ninu Ina lọ gbere, (2) okunfa....
Iroyin Alujannah ati Awọn Olugbe rẹ - (Èdè Yorùbá)
1- Idanilẹkọ yii sọ nipa oniranran apejuwe nipa ibugbe Alujannah gẹgẹ bi awọn apejuwe yii se wa lati inu Alukuraani ati Sunnah Ojisẹ Ọlọhun. 2- Alaye lori awọn isẹ ti o maa nse okunfa wiwọ Alujannah gẹgẹ bi Ọlọhun ti se se iroyin rẹ lati inu Alukuraani ati Sunna.
Idanilẹkọ yii da lori awọn Iwa Abiyì ti a le kọ ẹkọ rẹ lati ara Anọbi Muhammad [Ikẹ ati ola Ọlọhun ki o maa ba a]
Itumọ jijẹ Ojisẹ Ọlọhun ati jijẹ Anọbi Ọlọhun - (Èdè Yorùbá)
Alaye lori iyatọ ti nbẹ laarin awọn Anobi ati Ojisẹ Ọlọhun pẹlu ọla ti nbẹ laarin wọn.
Awọn Amin Opin Aye - (Èdè Yorùbá)
(i) Awọn orukọ ti Ọjọ Ikẹhin njẹ, (ii) Igba ti aye yoo parẹ, ati wipe bawo ni o se sunmọ tabi jinna to.
Ninu Awọn Apẹẹrẹ Ọjọ Ikẹhin - Jijade Mahdi - (Èdè Yorùbá)
Ẹkunrẹrẹ alaye lori awọn orukọ pẹlu awọn iroyin Mahdi naa
Ninu Awọn Apẹẹrẹ Ọjọ Ikẹhin - Jijade Masiihu Dajjaal - (Èdè Yorùbá)
1 - Ọrọ nipa Masiihu Dajjaal gẹgẹ bi Ojisẹ Olọhun [Ikẹ ati ọla Ọlọhun ki o maa ba a] ti se apejuwe ati awọn iroyin rẹ fun wa. 2 - Agbegbe yii pese idahun si awọn ibeere yii: Se Masiihu Dajjaal nsẹmi lọwọ lọwọ, Njẹ yoo bimọ, ilu wo ni....

API



