×
Image

Die Ninu Awon Ewa Islam - (Èdè Yorùbá)

1- Oro waye ninu waasi yi lori Itumo gbolohun Islam ati alaye bi o se je wipe ijosin Ojise Olohun, iwa re ati ise re je apejuwe ti o daju fun itumo paapaa esin Islam. Oro si tun waye lori bi ’waayi’ se maa n so kale fun Ojise Olohun.....

Image

Pataki Adiọkan ti o Yanju - (Èdè Yorùbá)

Ọrọ nipa awọn ipilẹ adiọkan Musulumi, pataki mimọ amọdaju rẹ, lilo lati fi se isẹ se ati ipepe lọ sibẹ

Image

Nini Igbagbo si Ojo Ikehin - (Èdè Yorùbá)

Olubanisoro se alaye lekunrere ohun ti a npe ni Ojo Ikehin ati awon orisirisi oruko ti Olohun Allah fun un ninu Alukuraani, Olubanisoro si tun se alaye awon nkan ti Ojo Igbehin ko sinu.

Image

Igbagbọ si Ọjọ Ikẹhin - (Èdè Yorùbá)

Alaye itumọ nini igbagbọ nipa ọjọ Ikẹhin pẹlu ẹri rẹ lati inu Shẹriah

Image

Nnkan ti ààyè o gba awọn ọmọde musulumi lati ma mọ ọn - (Èdè Yorùbá)

Nnkan ti ààyè o gba awọn ọmọde musulumi lati ma mọ ọn

Image

Sisa kuro nibi aigbagbọ nínú bibẹ Ọlọhun lọ sí inu Isilaamu. - (Èdè Yorùbá)

Sisa kuro nibi aigbagbọ nínú bibẹ Ọlọhun lọ sí inu Isilaamu.

Image

Musulumi ni mi - (Èdè Yorùbá)

Musulumi ni mi

Image

ALAYE NIPA ESIN ISLAAM NISOKI - (Èdè Yorùbá)

No Description

Image

AL QUR’AN ALAPỌNLE PẸLU ITUMỌ RẸ NI EDE YORUBA - (Èdè Yorùbá)

AL QUR’AN ALAPỌNLE PẸLU ITUMỌ RẸ NI EDE YORUBA

Image

Awon Ijeri Mejeeji - (Èdè Yorùbá)

Awon Ijeri Mejeeji

Image

Lilo Si Ile Oluwa - (Èdè Yorùbá)

Lilo Si Ile Oluwa