1- Idanileko yi soro nipa bi arinrin-ajo ati alaare yoo se maa ki irun won laini fi wole tabi lo o lara tayo asiko re. 2- Kiki irun rakah merin ni meji ni ori irinajo ati ki alaare fi aawe sile ninu osu Ramadan ki o si gba a pada....
Yiyo Saka - (Èdè Yorùbá)
Oro nipa awon ohun ti a maa nyo Saka ninu won, ati oundiwon ti a o yo ninu awon nkan ti Saka wo, Olubanisoro si bere pelu Aayah Alukuraani ti o nso nipa ijiya ti nbe fun awon ti won maa nko dukia jo laiyo Saka ninu re.
Idajo Esin Lori Gbigba Aawe ni Ojo Jimoh - (Èdè Yorùbá)
Eyi ni alaye awon Hadisi ti o n so nipa awon ojo ti Shari’ah ko fun Musulumi lati maa gba aawe ninu won ati awon eko esin ti o ro mo won.
Alaye Awon Hadiisi nipa Gbigba Iwaju Eni ti o ba n ki Irun koja ninu Tira “Umdatul Ahkaam” - (Èdè Yorùbá)
Idanileko yi so alaye gbogbo awon idajo ti o ro mo gbigba iwaju eni ti o ba n ki irun koja, yala eni ti o fi nkan si iwaju re tabi eni ti ko fi nkankan si iwaju.
Eyi ni alaye awon Haadisi tinso nipa Eje Nkan Osu Obinrin lati inu tira ‘Umudatul Haakaam’, ti olubanisoro si s’alaye awon idajo esin ti o ro mo.
Alaye lori Awon Hadiisi ti o so nipa Gbigba Aawe ni ori Irinajo ninu tira Umdatul Ahkaam - (Èdè Yorùbá)
Idanileko yi so nipa awon eko ti Islam gbe kale fun eniti o ba ngba aawe gege bii yiyara fun isinu ati lilora lati je saari, bakannaa ni oludanileko tun so oro nipa asiko ti aawe maa nbere ati asiko ti o maa npari, o si tun so nipa bi....
Koko idanileko yi ni oro nipa itanran ti o nbe fun eni ti o ni ajosepo pelu eleto re ni osan Ramadan, oniwaasi se alaye re ni ekunrere o si tun menu ba awon idajo miran.
Idanileko yi so nipa awon idajo esin ti o ro mo irun pipe, oniwaasi so oro nipa re ni ifosiwewe nigbati o nse alaye awon hadiisi ti o ro mo o.
Eleyi ni itumo awon hadiisi kan ti o so nipa sakaatul fitri ti awon Yoruba npe ni jaka. Oniwaasi se alaye awon idajo esin ti o ro mo o gege bii awon ti o ye ki o yo o, irufe ounje ti a fi maa nyo o ati odiwon ti....
Awon Idajo Esin Nipa Aja Ati Egbin re - (Èdè Yorùbá)
Idanileko yi je alaye nipa hadiisi eleekefa ninu tira “Umdatul Ahkaam”. Oludanileko so nipa egbin aja ati awon idajo ti o ro mo o, o si tun so nipa awon agbegbe ti esin ti gba awa Musulumi laaye lati se anfaani lara aja gege bii fifi so ile ati beebee....
Ibanisoro yi da lori Pataki odun mejeeji ninu Islam: odun itunu aawe ati odun ileya, olubanisoro si so bi ojise Olohun se gba awa Musulumi ni iyanju lori kiko awon ara ile wa lo si aaye ikirun ni ojo odun. Ni afikun, o tun so die nipa idajo Janaba ati....
The Rites Of Hajj And Umra(Piligramme And Minor Piligramme) - (Èdè Yorùbá)
No Description