Idanilẹkọ ti o se alaye: (1) Idajọ ẹran ti Musulumi ba pa, yala o da orukọ Ọlọhun si ni tabi ko da orukọ Ọlọhun si ni latari igbagbe. (2) Idajọ Ẹran ti Yahudi tabi Nasara ba pa yala fun ọdun ni tabi fun nkan miran. (3) Idajọ gbogbo ẹran ti....
Idajọ ki Musulumi jẹ Ẹran ti Yahudi ati Nasara ba pa - (Èdè Yorùbá)
Ẹkọ nipa Apejẹ igbeyawo (Walimatu-Nikah) - (Èdè Yorùbá)
Idanilẹkọ yi sọ nipa idajọ ki eniyan se ounjẹ lati fi ko awọn eniyan lẹnu jọ ati bẹẹ bẹẹ lọ ninu awọn ẹkọ ti o rọ mọ apejẹ sibi igbeyawo (walimọtu- nikahi).
Awọn Idajọ ti o rọ mọ Oku - (Èdè Yorùbá)
1- Ninu idanilẹkọ yii ọrọ waye nipa awọn ojuse ti Islam fẹ fun ẹni ti ko ni alaafia lati se ati awọn ojuse ti Ẹsin fẹ fun awọn olutọju rẹ ki wọn se fun un. 2- Itẹsiwaju ninu alaye awọn ojuse ti Islam fẹ fun awọn olutọju alaare lati se....
Awọn Ẹko ti o rọ mọ Ọmọ-ọdọ tabi Osisẹ ti a gba si isẹ - (Èdè Yorùbá)
Alaye ni ẹkunrẹrẹ waye ninu idanilẹkọ yii lori ẹkọ ti o rọ mọ gbogbo ẹni ti n se isẹ sin eniyan.
Asigbọ lori Akoko Irun Jimọh - (Èdè Yorùbá)
Idanilẹkọ yii se alaye ọrọ awọn onimimọ ti o da lori igba ti o yẹ ki a maa ki Irun Jimọh, ni idahun si asigbọye ẹsin eyi ti o n waye lati ọwọ ikọ awọn ọdọ Musulumi kan ti wọn ngbe Irun Jimọh duro ni aago mẹsan awurọ.
Ẹran ikomọjade ati awọn idajọ ti o rọ mọ ọ - (Èdè Yorùbá)
Alaye ohun ti o njẹ ẹran ikomọjade ati awọn ẹri ti o tọka si i ninu Sunna. Alaye awọn idajọ ẹran ikomọjade pẹlu sisọ awọn majẹmu ti o rọ mọ ọ. Abala yii ni oludanilẹkọ ti jẹ ki a mọ boya a le se ẹran ikomọjade ni ọbẹ, ki a....
Awọn Aisedeede ti o maa nsẹlẹ pupọ lori Irun - (Èdè Yorùbá)
Pataki irun kiki ati wipe ohun ni akọkọ ohun ti Musulumi yoo se isiro rẹ ni ọjọ ajinde. Diẹ ninu awọn aisedeede naa gẹgẹ bii: aifarabalẹ, wiwo ọtun wosi lori irun ati bẹẹbẹẹ lọ.
Ọsọ Obinrin ninu Ẹsin Islam - (Èdè Yorùbá)
Idajọ ti o rọ mọ ọsọ obinrin sise pẹlu ojupọnna ti obinrin le gba se ọsọ ninu Islam
Awọn Ohun ti o maa njẹ ki ọmọ ya alaigbọran - (Èdè Yorùbá)
Diẹ ninu awọn okunfa ipanle, janduku ati aigbọran ti awọn ọmọ ya kalẹ si awujọ. Itẹsiwaju ninu alaye awọn okunfa ipanle pẹlu awọn ọna abayọ si awọn iwa buburu yii.
Iyakuya Ọmọ, ki ni awọn okunfa rẹ - (Èdè Yorùbá)
Awọn idi tabi okunfa ti awọn ọmọ ni awujọ wa loni fi nya alaigbọran
Apejuwe Ile Musulumi - (Èdè Yorùbá)
Idanilẹkọ ti o sọ pataki ile ati bi o se yẹ ki ile musulumi ri.
Ibẹru Ọlọhun ninu Irun kiki - (Èdè Yorùbá)
Awọn koko idanilẹkọ yii: (1) Alaye itumọ ibẹru Ọlọhun ninu irun kiki pẹlu apejuwe rẹ nibi isesi awọn ẹni-isaaju ti wọn jẹ ẹni-rere. (2) Itaniji si awọn isesi kan ti ko lẹtọ ninu irun. (3) Awọn ohun ti o le se okunfa ibẹru Ọlọhun ninu irun.

API

