Waasi yi da lori awon nkan ti yo maa je atona fun Musulumi losi ogba idera Al-janna, alakoko re ni adiokan ti o dara ti o jinna si ebo, eleekeji si ni ijosin ti o ni alaafia ti o wa ni ibamu pelu eyi ti ojise Olohun se.
Oju-ona si Ogba Idera (Al-janna) - 1 - (Èdè Yorùbá)
Oju-ona si Ogba Idera (Al-janna) - 2 - (Èdè Yorùbá)
Oniwaasi se alaye ni abala yi wipe ti awon onimimo esin ba nso oro nipa awon ijo ti yoo la ti yoo ba ojise Olohun wo Al-janna itumo re ni wipe awon ti won ba ntele ilana ojise naa, kiise gbogbo eniti o ba npe ara re ni oni sunna,....
Wiwa Alubarika Eyi Ti O To Ati Eyi Ti Ko To - 1 - (Èdè Yorùbá)
Alaye lekunrere nipa itumo Alubarika ninu Ede larubawa ati ninu Shari’ah, ati oro nipa pataki Alubarika ati idajo wiwa Alubarika latara nkan tabi nibi nkan.
Wiwa Alubarika Eyi Ti O To Ati Eyi Ti Ko To - 2 - (Èdè Yorùbá)
Alaye awon nkan ti awon eniyan fi nwa Alubarika ni ona eewo ati alaye awon nkan ti Alubarika wa nibe. Bakannaa ohun ti o fa asise awon eniyan nibi wiwa Alubarika, alaye si tun waye lori awon nkan eelo ti won so wipe Annabi- ike ati ola Olohun ki o....
AWON ONA TI ESU (SHATANI) FI MAA NDARI ENIYAN SI ONA ANU - (Èdè Yorùbá)
Waasi yi so nipa awon nkan pataki, ninu won ni: (1) Awon ona ti esu (shatani) maa ngba lati dari eniyan si ona anu. (2) Awon ohun ti esin Islam toka Musulumi si lati maa fi wa iso Olohun.
Waasi yi je idahun fun awon ibeere wonyi: (1) Kinni paapaa itumo fiferan Ojise Olohun? (2) Kinni idi ti Olohun fi royin Ojise Re pelu iwa rere nibi ti O ti so wipe: {Dajudaju ire (Anabi) ni o ni iwa ti o dara julo}. (3) Tani eni ti o je....
Apa keji yi so nipa awon nkan wonyi: (1) Awon eko ti o dara julo ti o wa nibi ibasepo Ojise Olohun pelu awon Saabe re. (2) Sise awon Musulumi ni ojukokoro sibi kikose Ojise Olohun nibi awon iwa re fun oore aye ati orun.
Ohun ti o ye ki Musulumi mo nipa Suufi - (Èdè Yorùbá)
Ibanisọrọ yii da lori awọn osuwọn tabi awọn ojupọnan ti Musulumi gbọdọ maa gbe isẹ ẹsin rẹ le ki o le jẹ atẹwọgba lọdọ Ọlọhun Allah.
Awọn Okunfa Lilekun ati Didinku Igbagbọ-1 - (Èdè Yorùbá)
Idanilẹkọ yii bẹrẹ pẹlu sisọ itumọ igbagbọ pẹlu orisi ọna ti a le gbọ ọ ye si, yala ninu adisọkan ni, tabi wiwi jade ni ẹnu, tabi fifi sisẹ se.
Awọn Okunfa Lilekun ati Didinku Igbagbọ-2 - (Èdè Yorùbá)
Abala yii se alaye wipe Igbagbọ maa nlekun, o si maa ndinku pẹlu awọn ẹri lati inu Alukuraani ati Hadisi.
Awọn Okunfa Lilekun ati Didinku Igbagbọ-3 - (Èdè Yorùbá)
Abala yii se ifọsiwẹwẹ awọn nkan ti o maa nse alekun igbagbọ musulumi pẹlu alaye rẹ.
Awọn Okunfa Lilekun ati Didinku Igbagbọ-4 - (Èdè Yorùbá)
Abala yii jẹ idahun si awọn ibeere olowo-iye-biye ti o waye ni ipari idanilẹkọ naa.

API

