Alaye lori awọn aburu ti ọti mimu nko ba ilera ọmọniyan, owona ati eto isuna orilẹ ede ati bẹẹ bẹẹ lọ ninu awọn igun ti ọti mimu nda aburu si.
Aburu Ọti mimu - (Èdè Yorùbá)
Awọn isę Hajj - (Èdè Yorùbá)
Awọn ise Hajj: Aworan ti a ṣe ni ede Yoruba, ti Sheikh Dr. Haitham Sarhan pese re, o ṣe alaye gbogbo ohun ti alalaji nilo, ni ipele ipele, ati ni ọna ti o dara ati ṣoki, ti o ṣe apejuwe pẹlu awọn aworan ati awọn aami, ki a le se....
Baa sese Aluwala Tan manfi Eepe se - (Èdè Yorùbá)
Baa sese Aluwala Tan manfi Eepe se
Igberun Duro - (Èdè Yorùbá)
Igberun Duro
Igbeyawo Ninu Islam - (Èdè Yorùbá)
Asepo ti o ni alubarika ni igbeyawo je laarin okunrin ati obinrin. Esin Islam gbe awon ilana kan kale fun Musulumi l’okunrin ati l’obinrin lati tele fun igbesi aye alayo. Eleyi ni ohun ti akosile yi so nipa re.
Ninu Awon Eko Irinajo fun Ise Haj Tabi Umrah - (Èdè Yorùbá)
Wiwa ojurere Olohun, kiko awon ese sile, siso enu aala Olohun, didunni mo iranti Olohun ati beebee lo ni awon eko ti akosile yi so nipa won. Eleyi si ni die ninu awon ojuse Musulumi ti o ba gbero lati se irinajo fun ise Haj tabi Umrah.
Eni ti o n beru aisan, kinni yoo se? - (Èdè Yorùbá)
Eleyi ni idahun fun ibeere lori bi eniyan kan ba n beru aisan.
Idajo ki eniyan to ni iduro - (Èdè Yorùbá)
Fatwa yi so fun wa nipa bi o ti je wipe eniyan leto lati to ni iduro bi o tile je wipe ipile ni ki eniyan bere nigbati o ba fe to.
Pataki Oro Omode ninu Islam - (Èdè Yorùbá)
Khutba yi da lori oro nipa awon omode ati bi won ti se Pataki ni awujo. Oniwaasi fi oro yi se khutuba ni ibamu pelu ojo ti orile-ede Nigeria mu gege bii ojo awon ewe (omode). O si se alaye pupo nipa bi esin Islam ti se amojuto awon omode.
Ola Osu Ramadan ati Ilana ti o to lori bibere Aawe nibe - (Èdè Yorùbá)
Ibanisoro yi se alaye ni ekunrere awon ola ti o n be fun osu Ramadan, ninu re si ni wipe Olohun daruko osu yi ninu Al-kurani ti ko si daruko osu miran leyin re. Ninu awon ola ti Olohun se fun osu yi ni wipe Olohun yoo pa ase wipe....
Ile Musulumi - 1 - (Èdè Yorùbá)
Ibanisoro yi da lori Ile Musulumi ati bi o se ye ki o ri. Olubanisoro so wipe ohun ti o se Pataki julo ki Musulumi mojuto ni ki o sa esa eni ti yoo fi se aya, ki obinrin Musulumi naa si sa esa eni ti yoo fi se oko.....
Ile Musulumi - 2 - (Èdè Yorùbá)
Olubanisoro so ninu apa keji waasi yi Pataki ki oko maa na owo le iyawo re lori, o si je ki a mo wipe ojuse ti Olohun se ni dandan fun un ni, Olohun si ti se adehun lati maa fi opolopo ropo ti o ba ti n na fun....

API





