Alaye nipa idajọ ibura pẹlu nkan miran ti o yatọ si Ọlọhun Allah, nigbati o maa n jẹ ẹbọ kekere ati nigbati o maa n jẹ ẹbọ nla.
Ibura Pẹlu Nkan Miran Ti o Yatọ si Ọlọhun - (Èdè Yorùbá)
Ẹsẹ ati ilapa rẹ lori ọmọniyan ati awujọ - 1 - (Èdè Yorùbá)
"[1] Awọn aburu ti ẹsẹ maa nse okunfa rẹ fun ẹnikọọkan ati awujọ. [2] Gbogbo idaamu ti o ba aye loni wa latara ẹsẹ dida".
Ẹsẹ ati ilapa rẹ lori ọmọniyan ati awujọ - 2 - (Èdè Yorùbá)
Abala yii kun fun ibeere ati idahun.
Iyatọ laarin Oogun ti o ba Islam mu ati Idan - 1 - (Èdè Yorùbá)
Alaye idajọ Islam lori oogun iwosan – ewe ati egbo ati awọn nkan miran ti o jẹ iwosan fun ọmọniyan.
Iyatọ laarin Oogun ti o ba Islam mu ati Idan - 2 - (Èdè Yorùbá)
Alaye lẹkunrẹrẹ lori idajọ oogun ti o ni ẹbọ ninu pẹlu awọn apẹẹrẹ rẹ.
Iyatọ laarin Oogun ti o ba Islam mu ati Idan - 3 - (Èdè Yorùbá)
Idajọ ẹni ti o n se oogun ẹbọ ni wọn se alaye rẹ ni abala yii.
Awọn Isẹ oloore ti Sharia pa lasẹ ninu Osu Oju Ọrun ati Adadasilẹ ti awọn Eniyan nse nibẹ 1 - (Èdè Yorùbá)
Awọn adadaalẹ pẹlu awọn isẹ oloore ti nbẹ ninu osu Muharram ati Osu Sọfar.
Awọn Isẹ oloore ti Sharia pa lasẹ ninu Osu Oju Ọrun ati Adadasilẹ ti awọn Eniyan nse nibẹ 2 - (Èdè Yorùbá)
Alaye lori awọn adadaalẹ pẹlu awọn isẹ oloore ti nbẹ ninu awọn osu oju ọrun: Osu Rọbiul-Awwal titi de Dhul Hijjah.
Awọn Isẹ oloore ti Sharia pa lasẹ ninu Osu Oju Ọrun ati Adadasilẹ ti awọn Eniyan nse nibẹ 3 - (Èdè Yorùbá)
Adadaalẹ ti o ma nwaye nibi isẹ hajj sise, ti idahun si ibeere si jẹ ohun ti o tẹlee.
Awọn Isẹ oloore ti Sharia pa lasẹ ninu Osu Oju Ọrun ati Adadasilẹ ti awọn Eniyan nse nibẹ 4 - (Èdè Yorùbá)
Afikun idahun si ibeere.
Orukọ Ọlọhun ( Ar-Rahmaan ) - (Èdè Yorùbá)
Awọn ohunatiaworanniede Yoruba pẹluakọle: [Awọn OrukọỌlọhunti O Rẹwajulọni sisẹ n tẹle], niapayiini a tiriOrukọỌlọhun [ Ar-Rahmaan ], pẹlu awọn itumọti O n tọkasi, ọnaakọsilẹ rẹsidaraniriri.
Orukọ Ọlọhun ( Ar-Rọhiim ) - (Èdè Yorùbá)
Awọn ohunatiaworanniede Yoruba pẹluakọle: [Awọn OrukọỌlọhunti O Rẹwajulọni sisẹ n tẹle], niapayiini a tiriOrukọỌlọhun [ Ar-Rọhiim ], pẹlu awọn itumọti O n tọkasi, ọnaakọsilẹ rẹsidaraniriri.

API


