×
Image

Ilana Muhammad – ki ikẹ ati ọla Ọlọhun maa ba a – nibi awọn ijọsin rẹ ati awọn ibaṣepọ rẹ ati awọn iwa rẹ - (Èdè Yorùbá)

Ilana Muhammad – ki ikẹ ati ọla Ọlọhun maa ba a – nibi awọn ijọsin rẹ ati awọn ibaṣepọ rẹ ati awọn iwa rẹ

Image

Ọrọ ṣoki nipa adisọkan ti Isilaamu - (Èdè Yorùbá)

Ọrọ ṣoki nipa adisọkan ti Isilaamu

Image

Ọrọ nipa idajọ idan ati ṣíṣe yẹ̀míwò. - (Èdè Yorùbá)

Ọrọ nipa idajọ idan ati ṣíṣe yẹ̀míwò.

Image

1- Adiokan Ododo ati Awon Ohun ti o nyoni kuro ninu Islam. 2- Idanileko nipa Islam - (Èdè Yorùbá)

Iwe yi so nipa awon ohun ti o je dandan fun Musulumi lati mo ninu esin re papaajulo lori imo adiokan

Image

Adisọkan Awọn Ahlus-Sunnah Wal-Jamaa’ah - (Èdè Yorùbá)

No Description

Image

Agboye Adadaale ninu Esin ni odo Awon ti won wa ni oju ona Sunna - (Èdè Yorùbá)

Ibanisoro yi so ni ekunrere nipa itumo adadaale ninu esin pelu awon eri lati inu Al-kurani ati Sunna Ojise. O si se alaye ewu ti o wa nibi ki musulumi maa tele awon ti won ba n da adadaale ninu esin. Ni afikun, o tun se alaye awon majemu ti....

Image

Adiokan Awon Imaamu Mereerin ni odo Awon oni Sunna - (Èdè Yorùbá)

Ibanisoro yi da lori oro nipa adiokan Imam Abu Haniifa, biotile je wipe olubanisoro menu ba adiokan awon Imaamu mereerin. Ohun ti o si se okunfa eleyi ni bi apa kan ninu awon alaimokan ni awujo se npe Imaam Abu Haniifa ni keeferi nitori awon iruju kan ti o nbe....

Image

Alaye Lori Awon Iruju ti o nbe fun Awon Eniyan Kan nipa Wiwa Ategun (At-tawassul) - (Èdè Yorùbá)

Ibanisoro yi da lori alaye ni ekunrere lori awon iruju ti o nbe fun awon eniyan kan nipa awon ohun ti o leto ki Musulumi maa fi se ategun si odo Olohun ati awon nkan ti ko leto nigbati o ba npe Olohun.

Image

Ojise Aanu - (Èdè Yorùbá)

1- Oro lori koko ohun ti Olohun fi ran ojise Re Muhammad, iranse ni o je si gbogbo aye patapata. 2- Pelu bi o ti je wipe awon osebo fi inira kan ojise Olohun ni ilu Makka sibe sibe o tun fi aanu bawon lo ti ko si fi ibi....

Image

Ninu Awon Iruju Jamaa Ahmadiyya (Qoodiyaaniyyah) - (Èdè Yorùbá)

1- Eleyi ni iforowero laarin Ijo Ahmadiyyah ati Ijo Tadomun Muslimeen lori wipe se Annabi Isa- ike ati ola Olohun ki o maa ba a- ku si ori igi agbelebu ni tabi ko ku, se won gbe gun Sanmo lo ni tabi o wa ni ibikan lori ile aye yii.....

Image

Ẹbọ sise: Itumọ rẹ ati Awọn Ipin rẹ - (Èdè Yorùbá)

Idanilẹkọ yi da lori wipe idakeji ẹbọ sise ni sise Ọlọhun Allah ni aaso tabi gbigba A ni okan soso pẹlu ẹri Alukuraani ati ẹgbawa hadisi. Alaye tẹsiwaju nipa itumọ ẹbọ sise pẹlu awọn ọna ti ẹbọ sise pin si.

Image

Ọranyan titẹle Asẹ Ọlọhun Allah ati Asẹ Ojisẹ - (Èdè Yorùbá)

Idanilẹkọ yi da lori wipe titẹle asẹ Ọlọhun ati asẹ Ojisẹ Rẹ (ike ati ola Ọlọhun ki o maa ba a) ni ojulowo ẹsin. Alaye si tun waye nipa wipe sise ọjọ ibi Anọbi (Maoludi Nabiyi) ko ba ofin ẹsin Islam mu pelu awọn ẹri.