×
Image

Awọn Ẹbọ sise ti apakan ninu awọn Musulumi ko fiye si - (Èdè Yorùbá)

Idanilẹkọ ti o se alaye siso gbekude mọ ara, gbere sinsin ati nkan miran ti o fi ara pẹẹ lara awọn ohun ti o jẹ mọ ẹbọ sise.

Image

Ẹbọ sise: Itumọ rẹ ati Awọn Ipin rẹ - (Èdè Yorùbá)

Idanilẹkọ yi da lori wipe idakeji ẹbọ sise ni sise Ọlọhun Allah ni aaso tabi gbigba A ni okan soso pẹlu ẹri Alukuraani ati ẹgbawa hadisi. Alaye tẹsiwaju nipa itumọ ẹbọ sise pẹlu awọn ọna ti ẹbọ sise pin si.

Image

Ibura Pẹlu Nkan Miran Ti o Yatọ si Ọlọhun - (Èdè Yorùbá)

Alaye nipa idajọ ibura pẹlu nkan miran ti o yatọ si Ọlọhun Allah, nigbati o maa n jẹ ẹbọ kekere ati nigbati o maa n jẹ ẹbọ nla.

Image

Awọn Asa ti o ba Islam mu ati eyi ti o tako Islam - (Èdè Yorùbá)

Waasi oniyebiye ti o sọ nipa awọn asa ti o dara ti ẹsin Islam kin lẹyin, bakannaa awọn asa ti ko dara ti Islam kọ fun awa Musulumi.

Image

Asa ati Ẹsin - (Èdè Yorùbá)

Idanilẹkọ ti o n se alaye awọn nkan ti o n ba ẹsin jẹ mọ Musulumi lọwọ ti apa kan ninu awọn eniyan si n pe ni asa.

Image

Awọn Nkan ti Apa kan Ninu Awọn Musulumi fi maa n bura Yatọ si Ọlọhun - (Èdè Yorùbá)

Akọsilẹ ti o sọ diẹ ninu awọn nkan ti apa kan ninu awọn alaimọkan Musulumi fi maa n se ibura ti o si lodi si ilana ẹsin Islam.

Image

Esin Islam ati Asa - (Èdè Yorùbá)

Waasi yi so nipa asa ati esin Islam, olubanisoro pin asa si meji: eyi ti o dara ati eyi ti ko dara. Lehinnaa o so wipe esin Islam fi awon eniyan sile lori asa ti won nse ti o dara o si ko fun won nibi eyi ti ko dara....