Abala yii kun fun ibeere ati idahun.
Ẹsẹ ati ilapa rẹ lori ọmọniyan ati awujọ - 2 - (Èdè Yorùbá)
Ẹsẹ ati ilapa rẹ lori ọmọniyan ati awujọ - 1 - (Èdè Yorùbá)
"[1] Awọn aburu ti ẹsẹ maa nse okunfa rẹ fun ẹnikọọkan ati awujọ. [2] Gbogbo idaamu ti o ba aye loni wa latara ẹsẹ dida".
Awọn Ohun Eewọ ti apakan ninu awọn Musulumi fi ọwọ yẹpẹrẹ mu - (Èdè Yorùbá)
Idanilẹkọ nipa awọn ohun eewọ ti o ti di gbajumọ ni awujọ wa ni ode oni pẹlu ẹri ikilọ awọn iwa ibajẹ yii lati inu Alukuraani ati Sunnah Anabi.
Aburu Iwa Agbere ( Sina ) - 2 - (Èdè Yorùbá)
Ọrọ nipa awọn okunfa iwa agbere (sina) ati idahun si awọn ibeere.
Aburu Iwa Agbere ( Sina ) - 1 - (Èdè Yorùbá)
"[1] Alaye ohun ti o njẹ iwa agbere ati wipe isẹ buburu ti Ọlọhun korira ni. [2] Diẹ ninu awọn oniranran aburu ti o rọ mọ iwa agbere.".
Awon Ese Nla - (Èdè Yorùbá)
Waasi yi da lori oro nipa awon ese nla. Olubanisoro si se alaye iyato ti o wa laarin awon ese nla ati kekere. O tun so nipa bi o ti se je ojuse Musulumi ki o mo wipe oranyan ni ki oun jinna si awon ese kekere ati nla.
Ninu Apẹẹrẹ Opin Aye ni Eefin ti yoo jade - (Èdè Yorùbá)
Alaye lori eefin nla kan ti yoo bo aye kan pẹlu aburu eefin naa.
Ẹsẹ ati Oripa rẹ lori igbesi aye ẹda - (Èdè Yorùbá)
Ohun ti o njẹ ẹsẹ, okunfa rẹ ati oripa ẹsẹ dida lori ẹnikọọkan
Idajo Islam lori Orin kiko ati Gbigbo - (Èdè Yorùbá)
Waasi yi so nipa idajo Islam lori orin kiko ati gbigbo. Oniwaasi mu awon eri ti o po wa lati inu Al-kurani ati hadiisi lori bi orin gbigbo ati kiko se je eewo ninu Islam. Bakannaa ni oro waye ninu waasi yi lori awon aburu repete ti o wa nibi....