×
Image

Agboye Adadaale ninu Esin ni odo Awon ti won wa ni oju ona Sunna - (Èdè Yorùbá)

Ibanisoro yi so ni ekunrere nipa itumo adadaale ninu esin pelu awon eri lati inu Al-kurani ati Sunna Ojise. O si se alaye ewu ti o wa nibi ki musulumi maa tele awon ti won ba n da adadaale ninu esin. Ni afikun, o tun se alaye awon majemu ti....

Image

Awọn Isẹ oloore ti Sharia pa lasẹ ninu Osu Oju Ọrun ati Adadasilẹ ti awọn Eniyan nse nibẹ 3 - (Èdè Yorùbá)

Adadaalẹ ti o ma nwaye nibi isẹ hajj sise, ti idahun si ibeere si jẹ ohun ti o tẹlee.

Image

Awọn Isẹ oloore ti Sharia pa lasẹ ninu Osu Oju Ọrun ati Adadasilẹ ti awọn Eniyan nse nibẹ 2 - (Èdè Yorùbá)

Alaye lori awọn adadaalẹ pẹlu awọn isẹ oloore ti nbẹ ninu awọn osu oju ọrun: Osu Rọbiul-Awwal titi de Dhul Hijjah.

Image

Awọn Isẹ oloore ti Sharia pa lasẹ ninu Osu Oju Ọrun ati Adadasilẹ ti awọn Eniyan nse nibẹ 1 - (Èdè Yorùbá)

Awọn adadaalẹ pẹlu awọn isẹ oloore ti nbẹ ninu osu Muharram ati Osu Sọfar.

Image

Isọrọ perengede lori pipe Shariah ati ewu dida adadaalẹ - (Èdè Yorùbá)

Isọrọ perengede lori pipe Shariah ati ewu dida adadaalẹ

Image

Ninu Awọn Okunfa Adadasilẹ - (Èdè Yorùbá)

Alaye nipa diẹ ninu awọn nkan ti o maa n se okunfa ki adadasilẹ tan kan ni awujọ gẹgẹ bii kikọlẹ awọn onimimọ lati fi ododo ẹsin mọ awọn eniyan, ati bẹẹ bẹẹ lọ

Image

Idajọ Nafila ni Ọjọ Alaruba ti o kẹhin ninu Osu Safar - (Èdè Yorùbá)

Idajo esin lori yiyan nafila ni ojo alaruba ti o kehin ninu osu Safar ati idajo esin lori wipe irufe nafila bee adadasile ninu esin ni.

Image

AWỌN ADADAALẸ INU OSU RAJAB - (Èdè Yorùbá)

Idahun si ibeere nipa wipe irun ti won n pe ni "solaatur-rogaaibi" ati sise adayanri ojo ketadinlogbon ninu osu Rajab fun awon ijosin kan, se awon nkan wonyi ni ipile ninu esin, idahun si waye wipe adadaale ni gbogbo re je.