Apa keji yi so nipa awon nkan wonyi: (1) Awon eko ti o dara julo ti o wa nibi ibasepo Ojise Olohun pelu awon Saabe re. (2) Sise awon Musulumi ni ojukokoro sibi kikose Ojise Olohun nibi awon iwa re fun oore aye ati orun.
Waasi yi je idahun fun awon ibeere wonyi: (1) Kinni paapaa itumo fiferan Ojise Olohun? (2) Kinni idi ti Olohun fi royin Ojise Re pelu iwa rere nibi ti O ti so wipe: {Dajudaju ire (Anabi) ni o ni iwa ti o dara julo}. (3) Tani eni ti o je....
Bi Ojise Olohun ti ko Awon Saabe re ni Eko - (Èdè Yorùbá)
Oro lori bi Annabi- ike ati ola Olohun ki o maa ba a- se ko awon Sahabe re ni eko ti aye won fi dara ti orun won naa si rorun.
Itẹsiwaju ọrọ lori itan Sa’eed ibn ‘Aamir Al-Jumahi [Ki Ọlọhun yọnu si i].
Pataki awọn Sọhaba nipa wipe ẹni abiyi ni wọn ati itan ọkan ninu awọn Sọhaba eyi tii se Sa’eed ibn ‘Aamir Al-Jumahi [Ki Ọlọhun yọnu si i].
Ẹkọ Ninu Igbesi Aye Iya wa Khadijah [Ki Ọlọhun yọnu si i] -3 - (Èdè Yorùbá)
Awọn ọla ti n bẹ fun Iya wa Khadijah, ti ibeere ati idahun si tẹle e.
Ẹkọ Ninu Igbesi Aye Iya wa Khadijah [Ki Ọlọhun yọnu si i] -2 - (Èdè Yorùbá)
Diẹ ninu awọn iwa ti o rẹwa ti o n bẹ fun Iya wa Khadijah, ti wọn si tun sọ diẹ lara awọn ọla ti o n bẹ fun un.
Ẹkọ Ninu Igbesi Aye Iya wa Khadijah [Ki Ọlọhun yọnu si i] -1 - (Èdè Yorùbá)
Khadijah jẹ ẹniti awọn ara ilu Mẹkkah gba pe o mọ ninu awọn obinrin ki ẹsin Islam too de, oun si ni ẹni akọkọ ti o kọkọ gba Islam.