Diẹ nipa ete awọn Ijọ Shia fun awa Musulumi ti a wa lori Sunna Anabi wa Muhammad [Ikẹ ati ọla Ọlọhun ki o maa ba a].
Igbagbọ Ijọ Shia – 3 - (Èdè Yorùbá)
Igbagbọ Ijọ Shia – 2 - (Èdè Yorùbá)
Alaye ni ẹkunrẹrẹ nipa adiọkan awọn Ijọ Shia: Adiọkan wọn nipa awọn Saabe Ojise Ọlọhun [Ikẹ ati ọla Ọlọhun ki o maa ba a], adiọkan wọn si Alukuraani ati bẹẹbẹẹ lọ.
Igbagbọ Ijọ Shia – 1 - (Èdè Yorùbá)
Alaye nipa bi Ijọ Shia se bẹrẹ pẹlu itọkasi wipe Yahuudi ni ẹni ti o pilẹ Ijọ Shia.
DIẸ NINU ADISỌKAN AWỌN ALASEJU NINU AWỌN SUUFI - (Èdè Yorùbá)
Akọsilẹ yii sọ diẹ ninu adisọkan awọn Suufi nipa ojisẹ Ọlọhun ati diẹ ninu adisọkan wọn nipa awọn ti a n pe ni waliyyul-lahi (Awọn ọrẹ Ọlọhun). A mu ọrọ naa wa lati inu tira “Almoosu’atul Muyassarah”.
Alaye nipa Ijọ Shii’ah - (Èdè Yorùbá)
1- Alaye nipa awọn ijọ ti njẹ Shii’ah ati wipe ki ni adisọkan wọn nipa Ọlọhun ati si Alukuraani 2- Igbagbọ ijọ Shii’ah si awọn Sahabe ati ipo ti wọn gbe awọn asiwaju wọn si 3- Alaye diẹ ninu awọn adisọkan wọn gẹgẹ bii:- Tukyah, Muta’h. Ti oludanilẹkọ si tun....
Ohun ti o ye ki Musulumi mo nipa Suufi - (Èdè Yorùbá)
Ibanisọrọ yii da lori awọn osuwọn tabi awọn ojupọnan ti Musulumi gbọdọ maa gbe isẹ ẹsin rẹ le ki o le jẹ atẹwọgba lọdọ Ọlọhun Allah.
Awon janmoo Islam ti o wa ni awujo ni anfaani pupo, awon ni won nse itoju awon omo Musulumi ti won ko je ki opolopo won ti sina tabi di keferi, won maa nse alaye esin fun awon omode ati odo ati agbalagba, bibe won ni awujo si je amin....