Gbigba Awe Ramadan
Gbigba Awe Ramadan - (Èdè Yorùbá)
Ola Osu Ramadan ati Ilana ti o to lori bibere Aawe nibe - (Èdè Yorùbá)
Ibanisoro yi se alaye ni ekunrere awon ola ti o n be fun osu Ramadan, ninu re si ni wipe Olohun daruko osu yi ninu Al-kurani ti ko si daruko osu miran leyin re. Ninu awon ola ti Olohun se fun osu yi ni wipe Olohun yoo pa ase wipe....
Idajo Esin Lori Gbigba Aawe ni Ojo Jimoh - (Èdè Yorùbá)
Eyi ni alaye awon Hadisi ti o n so nipa awon ojo ti Shari’ah ko fun Musulumi lati maa gba aawe ninu won ati awon eko esin ti o ro mo won.
Alaye lori Awon Hadiisi ti o so nipa Gbigba Aawe ni ori Irinajo ninu tira Umdatul Ahkaam - (Èdè Yorùbá)
Idanileko yi so nipa awon eko ti Islam gbe kale fun eniti o ba ngba aawe gege bii yiyara fun isinu ati lilora lati je saari, bakannaa ni oludanileko tun so oro nipa asiko ti aawe maa nbere ati asiko ti o maa npari, o si tun so nipa bi....
Koko idanileko yi ni oro nipa itanran ti o nbe fun eni ti o ni ajosepo pelu eleto re ni osan Ramadan, oniwaasi se alaye re ni ekunrere o si tun menu ba awon idajo miran.