×
Image

Idajo Islam lori Owo Ele (Riba) - (Èdè Yorùbá)

Idanilẹkọ yii se afihan iha ti Islam kọ si owo ele ni gbagba pẹlu idajọ rẹ ati orisi ọna ti owo ele ni gbigba pin si.

Image

Idajọ Tẹtẹ Tita Ninu Islam - 3 - (Èdè Yorùbá)

Abala yi so nipa awon idahun si ibeere lorisirisi ti o wa lori akole ibanisoro yi.

Image

Idajọ Tẹtẹ Tita Ninu Islam - 2 - (Èdè Yorùbá)

Itẹsiwaju ẹkunrẹrẹ alaye lori orisirisi awọn ọna ti tẹtẹ pin si, ti olubanisọrọ si jẹ ki a mọ awọn isesi ti tẹtẹ wọ ati eyi ti tẹtẹ ko wọ, pelu diẹ ninu abala ibeere ati idahun.

Image

Idajọ Tẹtẹ Tita Ninu Islam - 1 - (Èdè Yorùbá)

Ibanisọrọ ni abala yii da lori awọn koko wọnyii: (i) Kinni Itumọ Tẹtẹ tita, (ii) Awọn ẹri ti o se Tẹtẹ Tita ni eewọ lati inu Alukuraani mimọ ati awọn Haadisi pẹlu apanupọ ọrọ awọn onimimọ, (iii) Awọn ewu ti nbẹ nibi tẹtẹ tita.

Image

OWO- ELE (RIBA) - (Èdè Yorùbá)

Oniwaasi se alaye itumo aaya (276) ninu Suuratu Bakora, o si so ni ekunrere awon aburu ti o wa nibi ki eniyan maa gba owo ele.

Image

Awọn Ẹko ti o rọ mọ Ọmọ-ọdọ tabi Osisẹ ti a gba si isẹ - (Èdè Yorùbá)

Alaye ni ẹkunrẹrẹ waye ninu idanilẹkọ yii lori ẹkọ ti o rọ mọ gbogbo ẹni ti n se isẹ sin eniyan.