Abala yii jẹ alekun alaye lori awọn ohun ti o maa nmu igbesi aye lọkọ-laya ni itumọ ati idahun si awọn ibeere ti o waye.
Awọn Okunfa Igbesi Aye Idunnu fun Lọkọ-laya-2 - (Èdè Yorùbá)
Awọn Okunfa Igbesi Aye Idunnu fun Lọkọ-laya-1 - (Èdè Yorùbá)
Idanilẹkọ yii da lori itumọ lọkọ-laya ati alaye awọn ohun ti o maa njẹ ki igbesi aye lọkọ-laye ni itumọ gẹgẹ bii: Ibẹru Ọlọhun Allah, Sise akiyesi adehun ti ọkunrin maa nse fun obirin nigba ti wọn ko tii gbe ara wọn wọ ile.
Idẹkun Wahala laarin Lọkọ-Laya -3 - (Èdè Yorùbá)
Eyi ni abala idahun si awọn ibeere ti o jẹyọ lati ibi idanilẹkọ yii.
Idẹkun Wahala laarin Lọkọ-Laya -2 - (Èdè Yorùbá)
Abala yii sọ nipa awọn ọna mẹrin ti ede-aiyede ma ngba wa laarin lọkọ-laya, oludanilẹkọ si tun se alaye awọn igbesẹ ti Islam fẹ ki a gbe nigbati ede-aiyede ba waye laarin lọkọ-laya.
Idẹkun Wahala laarin Lọkọ-Laya -1 - (Èdè Yorùbá)
Alaye ni abala akọkọ Idanilẹkọ yii da lori awọn koko wọnyii: (i) Sisọ nipa pataki ati anfaani ti o wa nibi igbeyawo, (ii) Sise alaye awọn ojuse lati ọdọ ọkọ si iyawo rẹ, bẹẹ naa ni awọn ojuse lati ọdọ iyawo si ọkọ rẹ, (iii) Sise apejuwe oniranran ede-aiyede laarin....
Eto Oko ati Aya ninu Islam - (Èdè Yorùbá)
Ibanisoro se alaye awon eto wonyi: (i) Eto oko lori aya, (ii) Eto Aya lori oko, (iii) Eto ti awon mejeeji ni si ara won.