Waasi yi so nipa bi o ti je wipe esin Islam menu ba gbogbo nkan patapata ti o fi de ibi eko bi a ti se n to tabi ya igbe, bawo ni Islam kose wa ni so nipa eto bi a se ndari ilu ati bi a se nse....
Ojuse Olori ati Awon ti won n dari ninu Islam - 1 - (Èdè Yorùbá)
Ojuse Olori ati Awon ti won n dari ninu Islam - 2 - (Èdè Yorùbá)
Eleyi ni apa keji ibanisoro naa, olubanisoro nso eyi ti o ku ninu awon majemu ti o ye ki o wa fun eniti a fe fi se olori ninu Islam.
Ojuse Asiwaju Si Awọn Ọmọlẹyin - (Èdè Yorùbá)
Alaye bi ẹsin Islam se pa asiwaju ni asẹ lati maa se ojuse rẹ lori awọn ọmọlẹyin rẹ, pẹlu apejuwe igbesi aye saabe agba Umar bin Khataab [Ki Ọlọhun Kẹ ẹ]
Esin Islam ati Oro nipa Oselu - (Èdè Yorùbá)
Ibanisoro yii da lori sise alaye nkan ti o nje Oselu ati oniranran eya oselu ti awon eniyan nse pelu nkan ti Islam gbe wa gege bi Eto Oselu.
Esin Islam ati Oro nipa Eto Oselu Tiwa- ntiwa (Demokiresi) - (Èdè Yorùbá)
1- Eleyi ni oro nipa ohun ti o je ojuse Musulumi nibi ibo didi ati idajo Islam lori kikopa ninu idibo. 2- Itesiwaju nipa ohun ti Islam so lori eto oselu tiwa- ntiwa (Demokiresi), olubanisoro menu ba idajo esin lori dida egbe oselu sile ati kikopa ninu re, o si....
Ẹtọ Adari ati Awọn ti wọn n dari - (Èdè Yorùbá)
Alaye lori awọn ojuse ati iwọ olori si awọn ti wọn ndari, bakannaa ojuse awọn ti wọn nse ijọba le lori si awọn adari

API


