×
Image

Pataki Adua ninu Islam - (Èdè Yorùbá)

Akọsilẹ ti o sọ nipa anfaani ti o n bẹ nibi adua fun Musulumi ododo ati bi o se jẹ ohun ti Ọlọhun fẹran lati ọdọ ẹru Rẹ.

Image

Ola Ti O Nbe Nibi Irun Kiki Ati Awon Anfaani Re - (Èdè Yorùbá)

Oore ti o po pupo ni o wa nibi irun kiki fun Musulumi. Ohun ni ona ti o dara julo lati wa asunmo si odo Olohun, o si maa nse okunfa aforiji fun Musulumi, bakannaa ni o je oluranlowo fun erusin lati wo ogba idera (al-Jannah).

Image

Ipo Irun Ninu Islam - (Èdè Yorùbá)

Akosile yi so nipa bi irun kiki ti se pataki to ninu esin Islam, ohun ni origun ti o lola julo leyin ijeri mejeeji, ohun naa si ni ise ti erusin maa n se ti o loore julo leyin won.

Image

Ọla ti o nbẹ fun Aluwala ati bi a ti se nse e - (Èdè Yorùbá)

Idanilẹkọ yii da lori alaye bi a se nse aluwala ati awọn ẹsan (ọla) ti o nbẹ fun aluwala sise, bakannaa ọrọ nipa awọn ohun ti o nsọ aluwala di ọranyan fun musulumi.

Image

Pataki Sise Adua Fun Ilu Ẹni - (Èdè Yorùbá)

Idanilẹkọ nipa awọn okunfa gbigba adua, ati wipe ẹniti o ba ni ifẹ si ilu rẹ gbọdọ maa se adua ki ilu naa dara.

Image

Pataki Adua - (Èdè Yorùbá)

Ibanisoro yi da lori adua ati pataki re. Adua ni ohun ti o je oranyan fun Musulumi lati maa se nigbakiigba ti o ba nfe nkan, ki o si doju adua naa ko Olohun re, ki o mase pe elomiran ayafi Oun.

Image

Pataki Adua ati Anfaani rẹ - (Èdè Yorùbá)

Khutuba yii da lori pataki adua sise ati anfaani to wa nibi adua sise Itẹsiwaju alaye lori pataki adua sise

Image

Ninu Awon Eko Irinajo fun Ise Haj Tabi Umrah - (Èdè Yorùbá)

Wiwa ojurere Olohun, kiko awon ese sile, siso enu aala Olohun, didunni mo iranti Olohun ati beebee lo ni awon eko ti akosile yi so nipa won. Eleyi si ni die ninu awon ojuse Musulumi ti o ba gbero lati se irinajo fun ise Haj tabi Umrah.

Image

Awọn Isẹ ti Ẹsan wọn yoo sẹku fun Musulumi lẹyin Iku - (Èdè Yorùbá)

Idanilẹkọ yii da lori awọn Isẹ ti ẹsan wọn maa nbe gbere lẹyin iku pẹlu apejuwe lati inu ẹgbawa hadisi.

Image

Anfaani yiyọ Saka (Zakat) fun Ẹnikọọkan ati fun Awujọ - (Èdè Yorùbá)

Alaye nipa ipo Saka yiyọ ninu ẹsin Islam ati awọn anfaani ti o wa nibi yiyọ rẹ yala ni abala ẹsin ni tabi abala iwa.

Image

Ola ti o wa fun Irun Pipe ati Awon Idajo Esin ti o sopo mo o - (Èdè Yorùbá)

Alaye nipa ola ti o nbe fun irun pipe ati awon idajo esin ti o ro m o o, olubanisoro se alaye wipe Ojise Olohun – ike ati ola Olohun ki o maa ba a- kii pe irun tabi se ikaama fun irun odun mejeeji: odun itunu aawe ati odun....