×
Image

Itọju Awọn Obi - (Èdè Yorùbá)

[1] Asọtẹlẹ lati ọdọ Ọlọhun Allah ni sise daada si obi ẹni. [2] Alukuraani ati ẹgbawa hadisi sọ nipa pataki daada sise si awọn obi mejeeji. [3] Apẹẹrẹ oniran-nran daada ti eniyan le maa se si awọn obi rẹ. [4] Awọn ojuse ọmọ si obi pẹlu awọn apejuwe ifisisẹse rẹ....

Image

Itoju Awon Obi Mejeeji - (Èdè Yorùbá)

Waasi yi so nipa pataki sise daradara si awon obi mejeeji ati bi Olohun ti se e ni dandan fun omo eniyan, beeni o tun se alaye esan nla ti o wa nibi ki eniyan maa se itoju won ati aburu ti o wa nibi sise aidaa si won.

Image

Sise Daadaa si Awon Obi Mejeeji ati Ikilo lori sise aburu si won - (Èdè Yorùbá)

Sise daadaa si awon obi je ojuse Pataki ti Olohun pa omo ni ase re leyin ti o pase wipe ko gbodo josin fun nkan miran yato si Oun Olohun. Eleyi ni ohun ti ibanisoro yi da lelori, olubanisoro si mu awon apejuwe lori oore ti o wa ninu ki....

Image

Dida Ebi Po - (Èdè Yorùbá)

Olubanisoro se alaye ohun ti o nje ebi, o si se alaye bakannaa bi o se ye ki eniyan maa da ebi re po. O tun se afikun anfaani ti o wa nibi ki eniyan maa da ebi po ati ijiya ti o wa nibi ki eniyan maa ja okun....

Image

Ojuse Musulumi si Ẹbi rẹ - (Èdè Yorùbá)

Akọsilẹ ti o n sọ nipa itumọ okun ibi, lẹhinnaa o tun se alaye ni ekunrẹrẹ awọn oore ti o wa nibi sise daadaa si awọn ẹbi ati aburu ti o wa nibi jija okun ẹbi.