Diẹ ninu awọn iranti Ọlọhun ti o yẹ ki Musulumi o mọ ki o si maa se ni ojoojumọ lati inu iwe Husnul Muslim.
Àwọn Sunnah Ànábì - (Èdè Yorùbá)
Èyí, nínú ìran rẹ̀, ni àkọ́kọ́ àkànṣe iṣẹ́ orí ẹ̀rọ-ayélujára, tó ní í ṣe pẹ̀lú ìmọ̀ ẹ̀rọ, èyí tó ní àkàkún pẹ̀lú ìlànà afaraṣe Ànábì – kí ìkẹ́ àti ọlà Ọlọ́hun máa bá a – àti àwọn ìrántí Ọlọ́hun tí ó máa ń ṣe ní ojoojúmọ́. Ó ń bá gbogbo....
Awọn Ọna ti o ba Ẹsin Islam mu fun Isọ Ọlọhun ati Aabo Rẹ - (Èdè Yorùbá)
Idanilẹkọ yii da lori awọn ọna ti musulumi fi le wa isọ Ọlọhun ati aabo Rẹ gẹgẹ bii: Jijẹ eso dabidun ‘ajiwa, sise aluwala loore koore, mima ki irun Fajri ni jama’a, mima ki irun oru, ati bẹẹ bẹẹ lọ.
Pataki Iranti Ọlọhun - (Èdè Yorùbá)
Idanilẹkọ yii sọ nipa awọn ẹsan ati pataki sise iranti Ọlọhun.
Awọn asikiri ti a maa sọ ni owurọ ati aṣalẹ - (Èdè Yorùbá)
Awọn asikiri ti a maa sọ ni owurọ ati aṣalẹ
Mó ń gbé síwájú rẹ, ìrẹ ọmọ-ìyá mi nínú ẹ̀sìn Islām, tí ó ń ka ìwé yìí; àwọn ìlànà Ànábì – kí ìkẹ́ àti ọlà Ọlọ́hun máa bá a – tí ó máa ń ṣe ní ojoojúmọ́ láti ìgbà tí ó bá ti jí, títí di ìgbà tí yóò sùn,....
Pataki Iranti Ọlọhun - (Èdè Yorùbá)
Akọsilẹ ti o sọ nipa pataki iranti Ọlọhun pẹlu awọn ẹri lati inu Alukurani ati hadiisi.
Akọsilẹ yii sọ diẹ ninu awọn asise ti apa kan ninu awọn Musulumi maa n se nibi iranti Ọlọhun, gẹgẹ bii kikojọ se iranti Ọlọhun, fifi asiko tabi onka si iranti Ọlọhun eyi ti kosi ninu Shẹria Islam.

API




