Ẹsin Isilaamu Eleyii ni akọsilẹ soki kan nipa ẹsin Isilaamu gẹgẹ bi o ṣe wa ninu Alikuraani alapọnle pẹlu Sunnah Anọbi : Tira pataki to ko alaye nipa ẹsin Isilaamu sinu, to nṣalaye eyi ti o pataki ju ninu awọn ìpìlẹ, ẹkọ ati awọn ẹwa rẹ lati inu awọn iwe-ẹri....
Die Ninu Awon Ewa Islam - (Èdè Yorùbá)
1- Oro waye ninu waasi yi lori Itumo gbolohun Islam ati alaye bi o se je wipe ijosin Ojise Olohun, iwa re ati ise re je apejuwe ti o daju fun itumo paapaa esin Islam. Oro si tun waye lori bi ’waayi’ se maa n so kale fun Ojise Olohun.....
AMỌNA ṢOKI FUN IFIHAN OYE ISLAM - (Èdè Yorùbá)
AMỌNA ṢOKI FUN IFIHAN OYE ISLAM
Idajo Dida ina sun Oku Omo Eniyan ninu Islam - 1 - (Èdè Yorùbá)
Ibanisoro yi da lori idajo Islam lori ki won da ina sun oku omo eniyan, Olubanisoro mu eri wa ninu hadiisi ojise Olohun lori wipe omo eniyan ni aponle leyin iku re bi o ti ni aponle nigbati o wa ni aaye. Haraam ni idajo ki won da ina sun....
Ojuse Eniyan Ni Ile Aye - (Èdè Yorùbá)
Akosile yi so nipa bi o ti se je wipe ko ba laakaye mu ki eniyan se nkan ti o dara ti o si tobi lai ni idi kankan, beenaani o se je wipe a ko gbodo lero wipe Olohun da eda eniyan pelu awon idera ti o po ti....
Awọn Ẹko ti o rọ mọ Ọmọ-ọdọ tabi Osisẹ ti a gba si isẹ - (Èdè Yorùbá)
Alaye ni ẹkunrẹrẹ waye ninu idanilẹkọ yii lori ẹkọ ti o rọ mọ gbogbo ẹni ti n se isẹ sin eniyan.
Ikẹ ati Aanu sise ninu Ẹsin Islam - (Èdè Yorùbá)
1- Alaye wa ninu idanilẹkọ yii lori: (1) Itumọ ikẹ ati aanu gẹgẹ bi awọn onimimọ ẹsin se se alaye rẹ. (2) Diẹ ninu awọn agbegbe ti ikẹ ati aanu ti gbodo maa waye gẹgẹ bii ki olori se ikẹ fun awọn ọmọlẹyin rẹ ati sise aanu fun awọn ọmọde.....