Afikun idahun si ibeere.
Awọn Isẹ oloore ti Sharia pa lasẹ ninu Osu Oju Ọrun ati Adadasilẹ ti awọn Eniyan nse nibẹ 2 - (Èdè Yorùbá)
Alaye lori awọn adadaalẹ pẹlu awọn isẹ oloore ti nbẹ ninu awọn osu oju ọrun: Osu Rọbiul-Awwal titi de Dhul Hijjah.
Awọn Isẹ oloore ti Sharia pa lasẹ ninu Osu Oju Ọrun ati Adadasilẹ ti awọn Eniyan nse nibẹ 1 - (Èdè Yorùbá)
Awọn adadaalẹ pẹlu awọn isẹ oloore ti nbẹ ninu osu Muharram ati Osu Sọfar.
Ayẹyẹ ọjọ ibi Anabi kosi ninu Ẹsin Islam - (Èdè Yorùbá)
Akọsilẹ ti o sọ nipa bi sise ayẹyẹ ọjọ ibi Anabi wa Muhammad se jẹ adadasilẹ ninu ẹsin, pẹlu awọn ẹri ti o rinlẹ.
Abala yii ni abala ibeere ati idahun.
Oludanilẹkọ sọ ni apa yii ọrọ awọn aafa ti wọn sọ wipe adadasilẹ sise ni ayẹyẹ ọjọ ibi Anabi (Ikẹ ati ọla Ọlọhun ki maa ba a) pẹlu awọn ẹri ti wọn fi rinlẹ lori awọn ọrọ wọn.
Oludanilẹkọ sọ ni apa yii ọrọ awọn aafa ti wọn sọ wipe ko si laifi nibi sise ayẹyẹ ọjọ ibi Anabi (Ikẹ ati ọla Ọlọhun ki maa ba a).
Ọrọ nipa bi sise ajọdun ọjọ ibi Anabi (Ikẹ ati ọla Ọlọhun ki maa ba a) se bẹrẹ.
Awọn ẹri lori wipe adadasilẹ ninu ẹsin ni sise ayẹyẹ ọjọ ibi Anabi [Ikẹ ati ọla Ọlọhun ki o maa ba a] ati bi ayẹyẹ naa se bẹrẹ.
Idajọ biba Keferi kopa ninu Ọdun wọn - (Èdè Yorùbá)
Idanilẹkọ yi sọ nipa itumọ biba awọn keferi kopa ninu ọdun wọn pẹlu awọn ẹri lorisirisi lori bi biba awọn keferi kopa ninu ọdun wọn se jẹ eewọ fun Musulumi.
Ọrọ Nipa Osu Rajab - (Èdè Yorùbá)
Alaye nipa awọn ohun ti o sẹlẹ ninu osu Rajab gẹgẹ bii osu ọwọ ati awọn osu ọwọ yoku.
Idajọ Nafila ni Ọjọ Alaruba ti o kẹhin ninu Osu Safar - (Èdè Yorùbá)
Idajo esin lori yiyan nafila ni ojo alaruba ti o kehin ninu osu Safar ati idajo esin lori wipe irufe nafila bee adadasile ninu esin ni.