Akọsilẹ ti o sọ nipa bi sise ayẹyẹ ọjọ ibi Anabi wa Muhammad se jẹ adadasilẹ ninu ẹsin, pẹlu awọn ẹri ti o rinlẹ.
Ayẹyẹ ọjọ ibi Anabi kosi ninu Ẹsin Islam - (Èdè Yorùbá)
Abala yii ni abala ibeere ati idahun.
Oludanilẹkọ sọ ni apa yii ọrọ awọn aafa ti wọn sọ wipe adadasilẹ sise ni ayẹyẹ ọjọ ibi Anabi (Ikẹ ati ọla Ọlọhun ki maa ba a) pẹlu awọn ẹri ti wọn fi rinlẹ lori awọn ọrọ wọn.
Oludanilẹkọ sọ ni apa yii ọrọ awọn aafa ti wọn sọ wipe ko si laifi nibi sise ayẹyẹ ọjọ ibi Anabi (Ikẹ ati ọla Ọlọhun ki maa ba a).
Ọrọ nipa bi sise ajọdun ọjọ ibi Anabi (Ikẹ ati ọla Ọlọhun ki maa ba a) se bẹrẹ.
Awọn ẹri lori wipe adadasilẹ ninu ẹsin ni sise ayẹyẹ ọjọ ibi Anabi [Ikẹ ati ọla Ọlọhun ki o maa ba a] ati bi ayẹyẹ naa se bẹrẹ.