Khutba yi so nipa bi Musulumi yoo se mura sile fun osu Ramadan lati gba aawe nibe ati lati se awon naafila nibe. O so nipa bi awon eni isiwaju ninu esin se maa n pade osu Ramadan pelu idunnu ati ayo, ti won si maa n banuje ti o....
Igbaradi fun Osu Awe Ramadan - 1 - (Èdè Yorùbá)
Igbaradi fun Osu Awe Ramadan - 2 - (Èdè Yorùbá)
Khutba yi so nipa oore ti o po ti Olohun se fun awa Musulumi pelu bi O ti se awon asiko kan ni adayanri fun awon ise oloore ti Musulumi yoo maa gba esan ti o po lori won. Ninu awon asiko naa si ni ojo Jimoh ati idameta oru....
Ola Osu Ramadan ati Ilana ti o to lori bibere Aawe nibe - (Èdè Yorùbá)
Ibanisoro yi se alaye ni ekunrere awon ola ti o n be fun osu Ramadan, ninu re si ni wipe Olohun daruko osu yi ninu Al-kurani ti ko si daruko osu miran leyin re. Ninu awon ola ti Olohun se fun osu yi ni wipe Olohun yoo pa ase wipe....

API

