2- Alaye lori awon idajo ti o sopo mo irun Jimoh, ninu won ni: (1) Asiko wo ni irun Jimoh maa n wole. (2) Onka wo ni o ye ki o pe ki a to le ki irun Jimoh. (3) Rakah melo ni Musulumi gbodo ba ki o to le....
Alaye nipa Irun Jimoh ninu tira Buluugul-maraam - (Èdè Yorùbá)
Akosile yi se alaye ni ekunrere lori hadiisi eleekesan ninu tira Arbaiina Nawawiyya, o si so opolopo ninu awon anfaani ti o ye ki Musulumi ni imo nipa re ninu hadiisi naa.
Hadiith ogoji ti o je ti Alufa wa Nawawiy - (Èdè Yorùbá)
Hadiith ogoji ti o je ti Alufa wa Nawawiy
Eleyi ni itumo awon hadiisi kan ti o so nipa sakaatul fitri ti awon Yoruba npe ni jaka. Oniwaasi se alaye awon idajo esin ti o ro mo o gege bii awon ti o ye ki o yo o, irufe ounje ti a fi maa nyo o ati odiwon ti....
Idanileko yi so nipa awon idajo esin ti o ro mo irun pipe, oniwaasi so oro nipa re ni ifosiwewe nigbati o nse alaye awon hadiisi ti o ro mo o.
Koko idanileko yi ni oro nipa itanran ti o nbe fun eni ti o ni ajosepo pelu eleto re ni osan Ramadan, oniwaasi se alaye re ni ekunrere o si tun menu ba awon idajo miran.
Alaye lori Awon Hadiisi ti o so nipa Gbigba Aawe ni ori Irinajo ninu tira Umdatul Ahkaam - (Èdè Yorùbá)
Idanileko yi so nipa awon eko ti Islam gbe kale fun eniti o ba ngba aawe gege bii yiyara fun isinu ati lilora lati je saari, bakannaa ni oludanileko tun so oro nipa asiko ti aawe maa nbere ati asiko ti o maa npari, o si tun so nipa bi....
Eyi ni alaye awon Haadisi tinso nipa Eje Nkan Osu Obinrin lati inu tira ‘Umudatul Haakaam’, ti olubanisoro si s’alaye awon idajo esin ti o ro mo.
Alaye Awon Hadiisi nipa Gbigba Iwaju Eni ti o ba n ki Irun koja ninu Tira “Umdatul Ahkaam” - (Èdè Yorùbá)
Idanileko yi so alaye gbogbo awon idajo ti o ro mo gbigba iwaju eni ti o ba n ki irun koja, yala eni ti o fi nkan si iwaju re tabi eni ti ko fi nkankan si iwaju.
1- Idanileko yi soro nipa bi arinrin-ajo ati alaare yoo se maa ki irun won laini fi wole tabi lo o lara tayo asiko re. 2- Kiki irun rakah merin ni meji ni ori irinajo ati ki alaare fi aawe sile ninu osu Ramadan ki o si gba a pada....
Alaye nipa imora oniyagbe (imora ti kosi omi nibe) ati awon idajo esin ti o so mo o.

API



