×
Image

Ninu Awon Eko Irinajo fun Ise Haj Tabi Umrah - (Èdè Yorùbá)

Wiwa ojurere Olohun, kiko awon ese sile, siso enu aala Olohun, didunni mo iranti Olohun ati beebee lo ni awon eko ti akosile yi so nipa won. Eleyi si ni die ninu awon ojuse Musulumi ti o ba gbero lati se irinajo fun ise Haj tabi Umrah.

Image

Eni ti o n beru aisan, kinni yoo se? - (Èdè Yorùbá)

Eleyi ni idahun fun ibeere lori bi eniyan kan ba n beru aisan.

Image

Yiyapa Ilana Awọn Asiwaju Ninu Ẹsin Nibi Itumọ Alukurani jẹ Okunfa Isina - (Èdè Yorùbá)

Ibanisoro yi da lori bi o ti je dandan fun Musulumi lati maa tele ilana awon asiwaju ninu esin papaajulo awon omoleyin ojise Olohun (Saabe) ati awon ti won tele won (Taabi’un) nigbati o ba fe mo itumo Alukurani Alaponle.

Image

Ninu Awọn Okunfa Adadasilẹ - (Èdè Yorùbá)

Alaye nipa diẹ ninu awọn nkan ti o maa n se okunfa ki adadasilẹ tan kan ni awujọ gẹgẹ bii kikọlẹ awọn onimimọ lati fi ododo ẹsin mọ awọn eniyan, ati bẹẹ bẹẹ lọ

Image

Awọn Nkan ti Apa kan Ninu Awọn Musulumi fi maa n bura Yatọ si Ọlọhun - (Èdè Yorùbá)

Akọsilẹ ti o sọ diẹ ninu awọn nkan ti apa kan ninu awọn alaimọkan Musulumi fi maa n se ibura ti o si lodi si ilana ẹsin Islam.