×
Image

Yiyapa Ilana Awọn Asiwaju Ninu Ẹsin Nibi Itumọ Alukurani jẹ Okunfa Isina - (Èdè Yorùbá)

Ibanisoro yi da lori bi o ti je dandan fun Musulumi lati maa tele ilana awon asiwaju ninu esin papaajulo awon omoleyin ojise Olohun (Saabe) ati awon ti won tele won (Taabi’un) nigbati o ba fe mo itumo Alukurani Alaponle.

Image

Kinni o nje Sunna ? - (Èdè Yorùbá)

Ibanisoro yi so nipa itumo sunna, o si je ki a mo igba ti awon Musulumi bere si pe awon kan ni oni sunna. Ni ipari alaye tun waye lori awon apeere ti a fi maa nda awon oni sunna mo; nitoripe opolopo naa ni won maa npe ara won....

Image

Ninu Awọn Okunfa Adadasilẹ - (Èdè Yorùbá)

Alaye nipa diẹ ninu awọn nkan ti o maa n se okunfa ki adadasilẹ tan kan ni awujọ gẹgẹ bii kikọlẹ awọn onimimọ lati fi ododo ẹsin mọ awọn eniyan, ati bẹẹ bẹẹ lọ

Image

Awon Nkan Ti O leto Fun Musulumi Lati Maa Fi Se Iwosan - (Èdè Yorùbá)

Alaye ni ekunrere wa ninu ibanisoro yi lori awon nkan ti o leto fun Musulumi lati maa lo fun idena arun ati lati wa iwosan nigbati arun ba n se e. Bakannaa ni oro tun waye lori awon oogun ti o leto fun Musulumi lati lo ti o si so....

Image

Awọn Nkan ti Apa kan Ninu Awọn Musulumi fi maa n bura Yatọ si Ọlọhun - (Èdè Yorùbá)

Akọsilẹ ti o sọ diẹ ninu awọn nkan ti apa kan ninu awọn alaimọkan Musulumi fi maa n se ibura ti o si lodi si ilana ẹsin Islam.