Idajọ ti o rọ mọ ọsọ obinrin sise pẹlu ojupọnna ti obinrin le gba se ọsọ ninu Islam
Ọsọ Obinrin ninu Ẹsin Islam - (Èdè Yorùbá)
Suuru ati erenje ti o nbẹ fun un - (Èdè Yorùbá)
Ninu idanilẹkọ yii: (1) Pataki suuru sise. (2) Ọna maarun ti suuru pin si. (3) Ẹsan rere ti nbẹ nibi suuru sise.
Tituuba nibi Ẹsẹ ati awọn majẹmu rẹ - (Èdè Yorùbá)
Alaye lori awọn majẹmu wiwa tituuba lọsi ọdọ Ọlọhun
Ẹsẹ ati Oripa rẹ lori igbesi aye ẹda - (Èdè Yorùbá)
Ohun ti o njẹ ẹsẹ, okunfa rẹ ati oripa ẹsẹ dida lori ẹnikọọkan
Awọn Ohun ti o maa njẹ ki ọmọ ya alaigbọran - (Èdè Yorùbá)
Diẹ ninu awọn okunfa ipanle, janduku ati aigbọran ti awọn ọmọ ya kalẹ si awujọ. Itẹsiwaju ninu alaye awọn okunfa ipanle pẹlu awọn ọna abayọ si awọn iwa buburu yii.
Iyakuya Ọmọ, ki ni awọn okunfa rẹ - (Èdè Yorùbá)
Awọn idi tabi okunfa ti awọn ọmọ ni awujọ wa loni fi nya alaigbọran
Apejuwe Ile Musulumi - (Èdè Yorùbá)
Idanilẹkọ ti o sọ pataki ile ati bi o se yẹ ki ile musulumi ri.
Ibẹru Ọlọhun ninu Irun kiki - (Èdè Yorùbá)
Awọn koko idanilẹkọ yii: (1) Alaye itumọ ibẹru Ọlọhun ninu irun kiki pẹlu apejuwe rẹ nibi isesi awọn ẹni-isaaju ti wọn jẹ ẹni-rere. (2) Itaniji si awọn isesi kan ti ko lẹtọ ninu irun. (3) Awọn ohun ti o le se okunfa ibẹru Ọlọhun ninu irun.
Awọn Ẹkọ ti o nbẹ fun jijẹ ati mimu - (Èdè Yorùbá)
1- Ninu abala yi ọrọ waye lori wipe ounjẹ ti Ọlọhun Allah pese fun wa idẹra ni o jẹ ati alaye idi ti o fi jẹ idẹra. Bakannaa awọn nkan ti o dara pupọ lati se akiyesi rẹ nigba ti a ba fẹ jẹ ounjẹ. 2- Abala yii jẹ itẹsiwaju....
Itumọ jijẹ Ojisẹ Ọlọhun ati jijẹ Anọbi Ọlọhun - (Èdè Yorùbá)
Alaye lori iyatọ ti nbẹ laarin awọn Anobi ati Ojisẹ Ọlọhun pẹlu ọla ti nbẹ laarin wọn.
Igbaradi fun Ọjọ Ikẹhin - (Èdè Yorùbá)
Idanilẹkọ lori bi o se yẹ ki a maa se ipalẹmọ fun ọjọ igbende tiise ọjọ ikẹhin
Awọn Amin Opin Aye - (Èdè Yorùbá)
(i) Awọn orukọ ti Ọjọ Ikẹhin njẹ, (ii) Igba ti aye yoo parẹ, ati wipe bawo ni o se sunmọ tabi jinna to.

API
