Waasi yi so nipa pataki sise daradara si awon obi mejeeji ati bi Olohun ti se e ni dandan fun omo eniyan, beeni o tun se alaye esan nla ti o wa nibi ki eniyan maa se itoju won ati aburu ti o wa nibi sise aidaa si won.
Itoju Awon Obi Mejeeji - (Èdè Yorùbá)
Itọju Awọn Obi - (Èdè Yorùbá)
[1] Asọtẹlẹ lati ọdọ Ọlọhun Allah ni sise daada si obi ẹni. [2] Alukuraani ati ẹgbawa hadisi sọ nipa pataki daada sise si awọn obi mejeeji. [3] Apẹẹrẹ oniran-nran daada ti eniyan le maa se si awọn obi rẹ. [4] Awọn ojuse ọmọ si obi pẹlu awọn apejuwe ifisisẹse rẹ....
Iyatọ laarin Oogun ti o ba Islam mu ati Idan - 1 - (Èdè Yorùbá)
Alaye idajọ Islam lori oogun iwosan – ewe ati egbo ati awọn nkan miran ti o jẹ iwosan fun ọmọniyan.
Iyatọ laarin Oogun ti o ba Islam mu ati Idan - 2 - (Èdè Yorùbá)
Alaye lẹkunrẹrẹ lori idajọ oogun ti o ni ẹbọ ninu pẹlu awọn apẹẹrẹ rẹ.
Iyatọ laarin Oogun ti o ba Islam mu ati Idan - 3 - (Èdè Yorùbá)
Idajọ ẹni ti o n se oogun ẹbọ ni wọn se alaye rẹ ni abala yii.
Esin Islam ati Asa - (Èdè Yorùbá)
Waasi yi so nipa asa ati esin Islam, olubanisoro pin asa si meji: eyi ti o dara ati eyi ti ko dara. Lehinnaa o so wipe esin Islam fi awon eniyan sile lori asa ti won nse ti o dara o si ko fun won nibi eyi ti ko dara....
ORO NIPA ESIN ISLAM NI ILE YORUBA - (Èdè Yorùbá)
Waasi yi so nipa awon asigboye esin ni odo awon iran Yoruba ti won da asa won po mo esin ti o si je wipe awon asa naa tako ohun ti esin Islam mu wa. Oniwaasi si menu ba awon asa ati ise kan ti o je wipe ebo sise....
IRIN AJO TI KO SE YE (IRIN AJO IKU) - (Èdè Yorùbá)
Oro nipa iku ati bi a se n we oku ni ilana esin Islam, pelu itoka si die ninu awon ohun ti o je dandan ki Musulumi ni igbagbo si lehin iku.
ORO NIPA AWON MALAIKA - (Èdè Yorùbá)
Oro waye ninu waasi yi lori itumo Malaika, ohun ti a gba lero pelu ki Musulumi ni igbagbo si Malaika, awon nkan ti Olohun fi sa won lesa ati wipe orisirisi ni won je.
Koko ohun ti ibanisoro yi da le lori ni: (1) Eto isejoba aye titun ni aburu ti yoo se fun awon ilu Musulumi, nibi eto oro-aje won ati awujo won. (2) Ohun ti oore aye ati ti orun wa nibe fun awa Musulumi ni ki a maa lo ofin Olohun....
Adanwo: Itumọ rẹ ati bi Musulumi yoo se se pẹlu rẹ 1/ 3 - (Èdè Yorùbá)
Itumọ adanwo ati orisirisi awọn aworan ti o maa ngba kan ọmọ’niyan.
Adanwo: Itumọ rẹ ati bi Musulumi yoo se se pẹlu rẹ 2/ 3 - (Èdè Yorùbá)
Adanwo ti o ba awọn Anọbi Ọlọhun, anfaani ti o wa nibi ki Ọlọhun fi adanwo kan Musulumi ati Okunfa adanwo.

API
