×
Image

Itọsọna fun Awọn ti nsise lara Ọkọ ati Awọn Onibara wọn - 1 - (Èdè Yorùbá)

Ninu apa kinni yi: (1) Itumọ Isẹ Ọwọ Sise pẹlu ẹri rẹ lati inu Alukuraani ati Sunnah. (2) Apejuwe ọkan-ọ-jọkan isẹ ọwọ ti Awọn Anọbi ti wọn ti rekọja lọ ti se lati fi wa jijẹ-mimu. (3) Ọrọ awọn onimimọ nipa iru isẹ ọwọ wo ni o dara julọ.

Image

Itọsọna fun Awọn ti nsise lara Ọkọ ati Awọn Onibara wọn - 2 - (Èdè Yorùbá)

Alaye lori Ojuse awọn atọkọse ati Imọran olowo iyebiye fun awọn atọkọse.

Image

Itọsọna fun Awọn ti nsise lara Ọkọ ati Awọn Onibara wọn - 3 - (Èdè Yorùbá)

Ikilo ati ipeni si akiyesi fun awọn atọkọse lori awọn isesi buburu ti o wọpọ laarin wọn, eyi ti wọn nfi ọwọ yẹpẹrẹ mu, ti ibeere ati idahun si jẹ ohun ti wọn fi kadi eto nilẹ.